Ò
Ogbe Ika speaks of the importance of patience, reflection, and valuing what you have.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE KINI
Ika ribiti ka bee
Adifa fun edun
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Edun loun ti sebo
Ikaribiti ika gbe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi orubo nitori omo ki osi rubo ki ara ti oba nda ole mon joju laarin awon egbe re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie meji
Eyele meji
Akuko adie meji
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ika gbemi njoba osorun
Ika o gbemi njoba ekiti efon
Adifafun orunmila
Baba nlole ba oba da ide oye
Ebo ni won no kose
Osi gbebo logbogba
Nje emi, oba gbe ide borun
Emi oba logbogba
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ire oye fun eleyi ki orubo sibe dada ki ole mun oye naa je gbe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Pepeye meji
Eyele meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ika gbemi njoba
Ika o gbemi noje oshorun Adifafun oni kamogun
Igbati nbe laarinota
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Nje kini o bawa kowa
Ota ko akika ko sai
Bawaka owo ota ko akika
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki orubo isegun ota if ape ota po fun eleyi ko rubo ki ota ole deyin leyin re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Agbebo adie meta
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
(4)
Ika gbemun gbemun
Awo agbe
Adifafun agbe
Ika gbemun gbemun
Awo aluko
Adifafun aluko
Ika gbemun gbemun
Awo odidere mofe
Adifafun odidere mofe
Won ni ki won orubo
Kaye ole ba ye won
Won si gbebo nbe won rubo
Ona epe ona ejin ewa
Bawa bayi ba peregede
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni kieeyan meta orubo ko le ba ye won papo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Opolopo igbin
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
(1)
Ori akika kan aojo pelu ewe ajilekegbe pelu odidi atare kan ao te ni odii ifa ikagbemi ao se adura si ao fi sin gbere si aarin ori eyi ti obaku ao mon fi foko mun laro laro
Explore Ifa
Ògbe Íká is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ogbe Oyeku, Ogbe Iwori, Ogbe Odi, Ogbe Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ògbe Íká Odu.
