Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òfún Òtúrá

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ofun Otua
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for strategic thinking and foresight.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/ofun-otura
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ofun Otua

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Boju oba roun bi okun Ki orun bide Adifafun ori Yoo la omo ata gutan sola Ebo won ni ose O si gbebo nibe orubo Ero ipo Ero ofa Agutan lawa fisola nilewa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifa yii ki elleyi orubo kole ba ni aje komo sin agutan ifa ni agutan tie naa basin ni odi ola

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Eyele Agbado Eko Epo Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Kiwotola kemi tola Adifafun won niga nnan Osinsin wonji ekun Omo ni wonsu Ebo won ni ki won o se Won si gbebo nibe won rubo Ruru ebo Eru atuka esu E wa bani nije butu omo ope nije butu omo laba ni lese oba orisa Ofun orate beyin gangan leyin olowota Eyin olowo ni o se gangan Kafi ete iwofa bo Iwofa oni fi tie sile Adifafun adegbosin ti se omo oba lode akure Ebo won ni o se O si gbebo nibe o rubo Nje, adegbosin awo rere Enikan o la labi adegbosin lode akure Adegbosin awo rere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni oju omo nip on elelyi ki orubo ko fi eku eja bofa ati agbebo adie ifa pere fun enito da ifayi ifa ni ki orubo kole bala ifani oju aje nipon elleyi korubo yo ni aje

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie Eku Eja Eko Epo Opolopo owo eye etu eyele igbin eko epo opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ada to pola lawo ile alara Ajiwebaku lawo oke ijero Okan nannan ajinan nan Adifafun orunmila Baba o fi yeye saya Bebedo ni mowo Ni mo fi tifa se Ofun rete ofun rete Ofun rete rete Adifafun orunmila Won ni ki baba o febo ola sile Ebo ajogun ni ki baba omo mun se O si gbebo ni be orubo Nje, mogbate mogbanaa Mogba gbogbo ajogun sadiju

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifayi ki elelyi orubo ikan enikan niyi toju aya npon toje pe obinrin kiorubo kole ba ri ibu joko aya ko fi adie agbada bo osun ifa ni ki eleyi orubo ajo gun kio logba gbogbo ile inu ilere dara dara ki o si lofi eran oruko kan rubo fesa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie Eku eja Eko Epo Opolopo owo Eran oruko kan Eko Epo Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ola kotola mokio lekan naa Tabakiwi lekeji emi ni se Adifafun kohunkoto Tise wole wode orisa Igba ti n momi oju sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni ki won o se Won gbebo ni be won rubo Nje kohunkoto irodo lo le kaje wale kohun koto irodo lole ko re gbogob wale Baba Gbaju Logi Gbingbe Tuntun a mon wo Adifafun alaye abufalaye Ebo ni won ni ki won o se Alaye nikan logbebo nibe lorubo Nje, alaye loku Le malaye sin Alasayi lesi ni leyin omore

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni ohun pere gbogbo fun elelyi ki eleyi orubo ire gbogbo kio si lobo kio sifi ruko rubo ifa ni ohun pere laiko fun elelyi ki elelyi orubo ki ire gbogbo ki ogun o abase fun ki ire ola ba wo le fi kio si fi ewure bo ifa pelu opa so funfun igaa kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran oruko kan igbin merindinlogun epo eko obi oti Eran ewure kan Igan aso funfun kan Epo Eko Obi Oti

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ikarahun igbin ori orisa ao oju ewe aje ao wa jo mejiji papo ao wa po mon ose dudu ao wa mon fi we ako ni lo gbogbo abuyi ta eyin toba ku ao da sinu oti oyinbo ao mon mu larolaro AWURE ao toju ewe omisinmisin itakun ewe ire ao wa lo mejeji papo ao wa fin se eyin adire mejo lepo niyo ao wa se adurasi ao wa je obe naa ti o badi oruganjo

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju iru ara aguntan ao toju egun ori gbigbe ao wa lo papo ao wa fi si gbere larija ao fi epo pupa la iyoku lori olo ti afi lolunkan daradara ewe segun sete ao toju ewe apada ao wa lopapo ao wa po mon ose dudu ao wa lo fi we lodo ti bansan lemeta ti aba de ilea o wa fi eja abori bo ori onitoun

Videos

Watch Òfún Òtúrá teachings on our channel.

Explore Ifa

Òfún Òtúrá is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ofun Otua. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Òfún Ogbè, Òfún Òyèkù, Òfún Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òfún Òtúrá Odu.