Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òfún Òkánràn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the need for adaptability and flexibility.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/ofun-okanran
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Okanran funfun minni Adifafun aje omo olopo oni Omo abani tule aye eni se Igba ti n ode orubo waye Ebo ni won ni kose Osi gbebo ni be orubo Nje aje loni so Fi so sile awo Aje loni so

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa nip e oun pere aje pupo fun eleyi ebo ni ki eleyi ose kole bani aje lowo kio si lobo aje pelu pepeye meji ati oyi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye meji Oyin Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Kanran kanran fun Kanran kanran ofun Adifafun duru Ti n momi oju sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni kose Ogbebo ni be orubo Nje oko gege kepe sinmi Moti deni apesin pintin pinti

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire apesin fun eleyi ki eleyi orubo ki o le bari eni pe si kio lofi ori eye osi fi akuko kan rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ori eye osin Agbon kan Akuko adire kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Monse Koran omo ipo Adifafun duru eyin ti yio paja Ojogbo je EBO ni weon ni kose Ogbebo nibe orubo Nje talapa ojogbo je Duru lopaja ojogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire asegbe fun eleyi ki eleyi orubo pe gbogbo oun ti bASE yio mon se ni ASEgbe kio rubo pelu aja kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aja kan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Okanran ni kotile fun roke Adifafun orisala osere mongbo Igba ti lo oko aileron lodun Ebo ni won ni kose Ogbebo nibe orubo Nje, talamonsi bi orun bape Orisa lamon sin toruba pe

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire gbogbo fun eleyi lati okore ebo nikose ki o si lobo orisale pelu opolopo igbin ati eye etu kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan Opolopo igbin Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju itanna tanna powo ao lo pelu iyere ao wa mu eran monlu ao gesi mokanle ni ogoji kekere ao wa seni epo ni yo ao wa se adurasi ao wa je obe naa

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju awo ilu duru ta bi awo ilu ara ao lo ao po mon ose dudu ao wa mon fiwe larolaro

Videos

Watch Òfún Òkánràn teachings on our channel.

Explore Ifa

Òfún Òkánràn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Òfún Ogbè, Òfún Òyèkù, Òfún Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òfún Òkánràn Odu.