Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Ofun Okanran

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu signifies the need for adaptability and flexibility.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/ofun-okanran
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Afinju ejo niga agbon
Ofinran eku nitona ja
Oja ni obe kun
Lonan korele lo le ma bewa
Adifafun olugedo elelyi tio teko lenpe omo asagijo Omo arin gijo
Omo afodi oko tale fo mo ga moga
Igba tinbe laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa nip e oun pere aje pupo fun
eleyi ebo ni ki eleyi ose kole
bani aje lowo kio si lobo aje
pelu pepeye meji ati oyi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye meji
Oyin
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Afefere nidun mope pere mo
Pepere aran gojo gojo nidun
Moko moja
Moko mojo moko
Mojo mokomojo aran
Adifafun ofun abufun olokanran
Nijo won nlole kanle Ija

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire apesin fun eleyi ki eleyi orubo ki o le bari eni pe si kio lofi ori eye osi fi akuko kan rubo fesu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ori eye osin
Agbon kan
Akuko adire kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Epepere nidun
Epepere epepere
Aran gojo gojo nidun mo komojo mokomojo Mokomojo aran
Adifafun Kori tii sunkun omo lo bode oyo Ebo won ni ose
O si gbebo nibe orubo
Nje, kori o are weyo
Fun mi lomo kan kin gbesere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni oun pe ire asegbe fun
eleyi ki eleyi orubo pe gbogbo
oun ti bASE yio mon se ni ASEgbe
kio rubo pelu aja kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aja kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Igi gbigbe abi akuo tutu nini
Adifafun lalule
Abufun lauluoko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni oun pe ire gbogbo fun
eleyi lati okore ebo nikose
ki o si lobo orisale pelu
opolopo igbin ati eye etu kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu kan
Opolopo igbin
Epo
Eko
Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju itanna tanna powo
ao lo pelu iyere ao wa mu
eran monlu ao gesi mokanle
ni ogoji kekere ao wa seni
epo ni yo ao wa se
adurasi ao wa je obe naa

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju awo ilu duru ta bi
awo ilu ara ao lo ao po
mon ose dudu ao wa mon fiwe
larolaro

Videos

Watch Ofun Okanran teachings on our channel.

Explore Ifa

Ofun Okanran is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ofun Okanran Odu.