Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Ofun Irosun

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Ofun Irosun
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of patience and perseverance.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/ofun-irosun
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Ofun Irosun

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ofun ro irosu ro
Adifafun oloun lawe
Tinbe laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni keleyi orubo aarin ota leleyi wa yio segun awon ota ti oba jawo leyin orun eleyi
ifanin won oman kunin
keleyi osi man se dada si
gbogbo eninyan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ofun roro ro
Irosun rororo
Adifafun alabahun ajapa
Oun opolo jo n sota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa loun pere isegun fun elelyi ebo ni komanru ota elelyi kanree ti eleyi nana si daman keleyi oman sora fun kosiman wipe kosinti ose nintori koman je pe kojo awada kojonkan nin yio fi wolesi eleyi lara
ifa pe ire fun eni toda ifayi
ko rubo si enu isere
ifa ni aje n pon eleyi korubo
ifa ni awon kan ba eleyi sota
nidi isere korubo kole bASE gun won

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Akuko adie kan
Owo
Eyele
Eye etu
Agbebo adie
Epo
Eko
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ofun rotiki babalawo
Oba lodifa fun
Oba tinfomin
Oju sogbere ire

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo nintori aje
ajenbofun eleyi
eyi yi ori ire aje lati pase
obinrin kan
ti eleyi bari ajenan tan
koman fibi su obinrin
nan nintori odo obinrin nan ninre re wa
Ifa pe ire fun eni to da ifayi ki elelyii o rubo ifa ni oju aya mi pon eleyi to ba se pe obinrin loda ifayi koru bo ibujoko ki aye ole ba bani ile oko re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
Eko
Epo
Agbebo adie
Akuko adie
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ofun ro irosunro
Adifafun ipile oro
Ti n fomi oju sogbere ire

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nin keleyi orubo
kosibo aje
nintori ajenbofun eleyi
omo ifa sinin elelyi
keleyi odi man ifa dada
keleyi oman fi eku eja abo adiekan obi oti owo koman ribofa
Ifa peire fun eni to da ifayi korubo ki aye ole ba gbatie
ki eleyi osi rubo ifa ni obinrin kan ni elelyi fe gba lowo awon kan korubo ifani awon to fe gbe obinrin yi ni agbara tabi nikankan ni eleyi fe gba lowo enikan korubo ko le bari gba tori eni naa magba na

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Eyele kan
Owo
Akuko adie
Agbebo adie
Eyele
Eko
Epo
Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Egbo elebue
Gbongbo toba tajannan
Eeso ikan
Odid atare kan
Aojo po
Aofi sin gbere meta meta lorike rike ara ao fi yoku fokomun
ti won fise obe wara ojo ao gun omo ose ao ko sinu ikefunfun ao mafi we loro laro pelu kankinkan tutu

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ifun aja tiwon fib o gun ifun agbo tiwon fibo sango ori aye lekeleke meta odidi atare meta ao jo po mo arawon ao ma fi fo eko tutu mun laro laro

Videos

Watch Ofun Irosun teachings on our channel.

Explore Ifa

Ofun Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Ofun Irosun. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ofun Irosun Odu.