Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òfún Íròsùn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Ofun Irosun
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of patience and perseverance.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/ofun-irosun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Ofun Irosun

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ofun ro irosu ro Adifafun oloun lawe Tinbe laarin ota Ebo won ni o se osi gbebo nibe o rubo Nje ota awoku ota awo rorun belebue Sokan yoo soriko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni keleyi orubo aarin ota leleyi wa yio segun awon ota ti oba jawo leyin orun eleyi ifanin won oman kunin keleyi osi man se dada si gbogbo eninyan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ofun roro ro Irosun rororo Adifafun alabahun ajapa Oun opolo jo n sota Ebo wonin won ose opolo ninkan ninbe Leyin tintubo Ero po ero ofa Eba nin laru segun Esin ni mawo ona koto koto Koto Adifafun apan olukoyin Igba tin fomioju sogbere ire Ebo ni won ni o se Osi gbebo nibe o rubo Ruru ebo Eru Atuka esu E wa ba ni ni je buture Ope jebutu ire Laba ni lese oba orisa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa loun pere isegun fun elelyi ebo ni komanru ota elelyi kanree ti eleyi nana si daman keleyi oman sora fun kosiman wipe kosinti ose nintori koman je pe kojo awada kojonkan nin yio fi wolesi eleyi lara ifa pe ire fun eni toda ifayi ko rubo si enu isere ifa ni aje n pon eleyi korubo ifa ni awon kan ba eleyi sota nidi isere korubo kole bASE gun won

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Akuko adie kan Owo Eyele Eye etu Agbebo adie Epo Eko Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ofun rotiki babalawo Oba lodifa fun Oba tinfomin Oju sogbere ire Ebo wonin ose Oba si gbebo nibe oba rubo Ero ipo Ero ofa E wa banin ni wowo ire Mo pe tikun pe tikun Emi o ri eni wesewese tin difa Mope eti osa peti osa Emi o reniyan tutu tin dibo Adifafun orunmila Baba o fi arede so binrin Ebo won ni ose O sigbebo nibe orubo Nje arede o aya awo Orunmila oni fi arede le lo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo nintori aje ajenbofun eleyi eyi yi ori ire aje lati pase obinrin kan ti eleyi bari ajenan tan koman fibi su obinrin nan nintori odo obinrin nan ninre re wa Ifa pe ire fun eni to da ifayi ki elelyii o rubo ifa ni oju aya mi pon eleyi to ba se pe obinrin loda ifayi koru bo ibujoko ki aye ole ba bani ile oko re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Eko Epo Agbebo adie Akuko adie Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ofun ro irosunro Adifafun ipile oro Ti n fomi oju sogbere ire Ebo wonin ose o gbebo nibe o rubo Kee pe Kee jinna Aje wa jede tututru Ofun wanrin wanrin Moja lailo oro n po to Iyun moja lailo meta la pasi Moja lailo meta aye Ti se obinrin ogberi Adifafun Orunmila Baba nlo lee gbeye Tiise obinrin ogberi Ebo won ni ose Osi gbebo nibe o rubo Nje yee yee ifa n gba ye lo Ogberi omo ti aye fib a fa lo ogberi o mo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nin keleyi orubo kosibo aje nintori ajenbofun eleyi omo ifa sinin elelyi keleyi odi man ifa dada keleyi oman fi eku eja abo adiekan obi oti owo koman ribofa Ifa peire fun eni to da ifayi korubo ki aye ole ba gbatie ki eleyi osi rubo ifa ni obinrin kan ni elelyi fe gba lowo awon kan korubo ifani awon to fe gbe obinrin yi ni agbara tabi nikankan ni eleyi fe gba lowo enikan korubo ko le bari gba tori eni naa magba na

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Eyele kan Owo Akuko adie Agbebo adie Eyele Eko Epo Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Egbo elebue Gbongbo toba tajannan Eeso ikan Odid atare kan Aojo po Aofi sin gbere meta meta lorike rike ara ao fi yoku fokomun ti won fise obe wara ojo ao gun omo ose ao ko sinu ikefunfun ao mafi we loro laro pelu kankinkan tutu

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ifun aja tiwon fib o gun ifun agbo tiwon fibo sango ori aye lekeleke meta odidi atare meta ao jo po mo arawon ao ma fi fo eko tutu mun laro laro

Videos

Watch Òfún Íròsùn teachings on our channel.

Explore Ifa

Òfún Íròsùn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Ofun Irosun. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Òfún Ogbè, Òfún Òyèkù, Òfún Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òfún Íròsùn Odu.