Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Adifafun oloun lawe
Tinbe laarin ota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifanin won oman kunin
keleyi osi man se dada si
gbogbo eninyan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Ese — Yoruba Verse
Irosun rororo
Adifafun alabahun ajapa
Oun opolo jo n sota
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pe ire fun eni toda ifayi
ko rubo si enu isere
ifa ni aje n pon eleyi korubo
ifa ni awon kan ba eleyi sota
nidi isere korubo kole bASE gun won
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Akuko adie kan
Owo
Eyele
Eye etu
Agbebo adie
Epo
Eko
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Oba lodifa fun
Oba tinfomin
Oju sogbere ire
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ajenbofun eleyi
eyi yi ori ire aje lati pase
obinrin kan
ti eleyi bari ajenan tan
koman fibi su obinrin
nan nintori odo obinrin nan ninre re wa
Ifa pe ire fun eni to da ifayi ki elelyii o rubo ifa ni oju aya mi pon eleyi to ba se pe obinrin loda ifayi koru bo ibujoko ki aye ole ba bani ile oko re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Owo
Eko
Epo
Agbebo adie
Akuko adie
Opolopo owo
Ese — Yoruba Verse
Adifafun ipile oro
Ti n fomi oju sogbere ire
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
kosibo aje
nintori ajenbofun eleyi
omo ifa sinin elelyi
keleyi odi man ifa dada
keleyi oman fi eku eja abo adiekan obi oti owo koman ribofa
Ifa peire fun eni to da ifayi korubo ki aye ole ba gbatie
ki eleyi osi rubo ifa ni obinrin kan ni elelyi fe gba lowo awon kan korubo ifani awon to fe gbe obinrin yi ni agbara tabi nikankan ni eleyi fe gba lowo enikan korubo ko le bari gba tori eni naa magba na
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eko
Agbado
Eyele kan
Owo
Akuko adie
Agbebo adie
Eyele
Eko
Epo
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Gbongbo toba tajannan
Eeso ikan
Odid atare kan
Aojo po
Aofi sin gbere meta meta lorike rike ara ao fi yoku fokomun
ti won fise obe wara ojo ao gun omo ose ao ko sinu ikefunfun ao mafi we loro laro pelu kankinkan tutu
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Explore Ifa
Ofun Irosun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Ifa Ofun Irosun. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ofun Irosun Odu.
