Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Ofun Otura

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ofun Otua
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu represents the need for strategic thinking and foresight.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/ofun-otura
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ofun Otua

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Boju oba roun bi okun
Ki orun bide
Adifafun ori
Yoo la omo ata gutan sola

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifa yii
ki elleyi orubo kole ba ni aje komo sin agutan ifa ni agutan tie naa basin ni odi ola

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie
Eyele
Agbado
Eko
Epo
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Kiwotola kemi tola
Adifafun won niga nnan
Osinsin wonji ekun
Omo ni wonsu
Ofun orate beyin gangan leyin olowota
Eyin olowo ni o se gangan
Kafi ete iwofa bo
Iwofa oni fi tie sile
Adifafun adegbosin ti se omo oba lode akure Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, adegbosin awo rere
Enikan o la labi adegbosin
lode akure
Adegbosin awo rere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifayi
ifa ni oju omo nip on elelyi ki
orubo ko fi eku eja bofa ati
agbebo adie
ifa pere fun enito da ifayi
ifa ni ki orubo kole bala ifani
oju aje nipon elleyi korubo yo ni aje

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie
Eku
Eja
Eko
Epo
Opolopo owo
eye etu
eyele
igbin
eko
epo
opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ada to pola lawo ile alara
Ajiwebaku lawo oke ijero
Okan nannan ajinan nan
Adifafun orunmila
Baba o fi yeye saya
Bebedo ni mowo
Ni mo fi tifa se
Ofun rete ofun rete
Ofun rete rete
Adifafun orunmila
Won ni ki baba o febo ola sile

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifayi
ki elelyi orubo ikan enikan
niyi toju aya npon toje pe
obinrin kiorubo kole ba ri ibu
joko aya ko fi adie agbada bo osun
ifa ni ki eleyi orubo ajo gun kio logba gbogbo ile inu ilere dara dara ki o si lofi eran oruko kan rubo fesa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie
Eku eja
Eko
Epo
Opolopo owo
Eran oruko kan
Eko
Epo
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ola kotola mokio lekan naa
Tabakiwi lekeji emi ni se
Adifafun kohunkoto
Tise wole wode orisa
Igba ti n momi oju sogbere ire gbogbo
Baba Gbaju Logi Gbingbe
Tuntun a mon wo
Adifafun alaye abufalaye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni ohun pere gbogbo fun elelyi
ki eleyi orubo ire gbogbo kio si
lobo kio sifi ruko rubo
ifa ni ohun pere laiko fun elelyi
ki elelyi orubo ki ire gbogbo ki
ogun o abase fun ki ire ola ba wo
le fi kio si fi ewure bo ifa
pelu opa so funfun igaa kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran oruko kan
igbin merindinlogun
epo
eko
obi
oti
Eran ewure kan
Igan aso funfun kan
Epo
Eko
Obi
Oti

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ikarahun igbin ori orisa
ao oju ewe aje ao wa jo mejiji
papo ao wa po mon ose dudu
ao wa mon fi we ako ni
lo gbogbo abuyi ta eyin toba ku
ao da sinu oti oyinbo ao mon
mu larolaro
AWURE
ao toju ewe omisinmisin itakun ewe ire ao wa lo mejeji papo ao wa fin se eyin adire mejo lepo niyo ao wa se adurasi ao wa je obe naa ti o badi oruganjo

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju iru ara aguntan ao toju
egun ori gbigbe ao wa lo papo
ao wa fi si gbere larija
ao fi epo pupa la iyoku lori
olo ti afi lolunkan daradara
ewe segun sete ao toju ewe apada
ao wa lopapo ao wa po mon
ose dudu ao wa lo fi we
lodo ti bansan lemeta ti aba
de ilea o wa fi eja abori
bo ori onitoun

Videos

Watch Ofun Otura teachings on our channel.

Explore Ifa

Ofun Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ofun Otua. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ofun Otura Odu.