Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Ofun Otura

Ofun Otura also known as Ofun Otua
Aliases: Ofun Otua
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for strategic thinking and foresight.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ofun-otura
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ofun Otua

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Boju oba roun bi okun Ki orun bide Adifafun ori Yoo la omo ata gutan sola

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifa yii ki elleyi orubo kole ba ni aje komo sin agutan ifa ni agutan tie naa basin ni odi ola

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Eyele Agbado Eko Epo Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Kiwotola kemi tola Adifafun won niga nnan Osinsin wonji ekun Omo ni wonsu Ofun orate beyin gangan leyin olowota Eyin olowo ni o se gangan Kafi ete iwofa bo Iwofa oni fi tie sile Adifafun adegbosin ti se omo oba lode akure Ebo won ni o se O si gbebo nibe o rubo Nje, adegbosin awo rere Enikan o la labi adegbosin lode akure Adegbosin awo rere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifayi ifa ni oju omo nip on elelyi ki orubo ko fi eku eja bofa ati agbebo adie ifa pere fun enito da ifayi ifa ni ki orubo kole bala ifani oju aje nipon elleyi korubo yo ni aje

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie Eku Eja Eko Epo Opolopo owo eye etu eyele igbin eko epo opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ada to pola lawo ile alara Ajiwebaku lawo oke ijero Okan nannan ajinan nan Adifafun orunmila Baba o fi yeye saya Bebedo ni mowo Ni mo fi tifa se Ofun rete ofun rete Ofun rete rete Adifafun orunmila Won ni ki baba o febo ola sile

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifayi ki elelyi orubo ikan enikan niyi toju aya npon toje pe obinrin kiorubo kole ba ri ibu joko aya ko fi adie agbada bo osun ifa ni ki eleyi orubo ajo gun kio logba gbogbo ile inu ilere dara dara ki o si lofi eran oruko kan rubo fesa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie Eku eja Eko Epo Opolopo owo Eran oruko kan Eko Epo Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ola kotola mokio lekan naa Tabakiwi lekeji emi ni se Adifafun kohunkoto Tise wole wode orisa Igba ti n momi oju sogbere ire gbogbo Baba Gbaju Logi Gbingbe Tuntun a mon wo Adifafun alaye abufalaye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa ni ohun pere gbogbo fun elelyi ki eleyi orubo ire gbogbo kio si lobo kio sifi ruko rubo ifa ni ohun pere laiko fun elelyi ki elelyi orubo ki ire gbogbo ki ogun o abase fun ki ire ola ba wo le fi kio si fi ewure bo ifa pelu opa so funfun igaa kan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eran oruko kan igbin merindinlogun epo eko obi oti Eran ewure kan Igan aso funfun kan Epo Eko Obi Oti

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ao toju ikarahun igbin ori orisa ao oju ewe aje ao wa jo mejiji papo ao wa po mon ose dudu ao wa mon fi we ako ni lo gbogbo abuyi ta eyin toba ku ao da sinu oti oyinbo ao mon mu larolaro AWURE ao toju ewe omisinmisin itakun ewe ire ao wa lo mejeji papo ao wa fin se eyin adire mejo lepo niyo ao wa se adurasi ao wa je obe naa ti o badi oruganjo

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju iru ara aguntan ao toju egun ori gbigbe ao wa lo papo ao wa fi si gbere larija ao fi epo pupa la iyoku lori olo ti afi lolunkan daradara ewe segun sete ao toju ewe apada ao wa lopapo ao wa po mon ose dudu ao wa lo fi we lodo ti bansan lemeta ti aba de ilea o wa fi eja abori bo ori onitoun

Videos

Watch Ofun Otura teachings on our channel.

Explore Ifa

Ofun Otura is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ofun Otua. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ofun Otura Odu.