Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òfún Ògundà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents strength and the ability to overcome obstacles.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/ofun-ogunda
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ofun figbin fekoko Awo Aderin Lodifafun aderin igba ti fomi oju sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni o se O si gbebo nibe orubo Nje, ofun figbin je ko ko ni gbayi gbindingbin din ni wa ni rinbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda ifayi ki elelyi orubo ni tori ire gbogbo ifa ni ki elelyi o lole figbin bo oke bori pelu isu koko

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Igbin Agbebo adie Isu koko Eko Epo Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Kekere eeko niya nan Agba eeko nioya rub Ita gbangba gbangba Awo Eko Lodifafun eeko Tise omo oloro kan atijo Ebo won ni ose O si gbebo nibe o rubo Nje, eeko nile o eeko lonan E wa wo bi Eeko gbesun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun eni toda fayi ifani korubo ki eni eleni mo bagbe iseere se ifa si ni ki eleyi ko mo yoju

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Agbe bo adie Eko Epo Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ta ba wole balele lakokoki Eni tio ki bale ile adabi afoju di Adifafun orunmila Baba lole ba ogun gbagun Eleye wole nimeko Ebo won ni ose O si gbebo nibe o rubo Nje, eleye wole mime Ko oro meko ose mun sere Mo eleye wole nimeko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni todafa yi ifa ni ki elleyi orubo pe awon agba niba elelyi ko rubo ebo meji niyo ru won o kan ikan mole modiesu okan ikan mole nidi esu pelu ori oruko won o pa oruko yi si ori EBO won o gbe ori re le wan owa kan mole midi esu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

oruko eekan agbado eko epo opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Otere loun iku ona Iku ojinan si alarun Adifafun orunmila Ti won n ranse iku pe lorun Ebo won ni ose O si gbebo nibe o rubo Nje, tan ni tanhin rere Awodi gbeku miralo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifa pere fun renitoda ifayi ki elelyi orubo laiku ifa ni eni kan niyi ti arun nse kiwon orubo fun kiwon o si fi oromo die kan kin eba ru oromodie ni won o fi se Fafun yow a lo ju si itagbangba ti a sa ti gbe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

akuko adie eko epo opolopo owo opa aso funfun 6 oromodie kan

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

AWURE ao toju ewe koko ati iyere ao wa bo igbin apinnu merin ao wa fi se ni epo ni yo ao wa ko obe yin si ori ifa ao wa je ni ojo keji

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

ao toju ewe segunsete ao toju ekolo ao wa gun mejeji mon ose dudu ao wa fui we fun ojo meta

Videos

Watch Òfún Ògundà teachings on our channel.

Explore Ifa

Òfún Ògundà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Òfún Ogbè, Òfún Òyèkù, Òfún Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òfún Ògundà Odu.