O
This Odu represents strength and the ability to overcome obstacles.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ofun figbin fekoko
Awo Aderin
Lodifafun aderin igba
ti fomi oju sogbere ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun eni toda ifayi
ki elelyi orubo ni tori ire gbogbo
ifa ni ki elelyi o lole figbin
bo oke bori pelu isu koko
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Igbin
Agbebo adie
Isu koko
Eko
Epo
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Kekere eeko niya nan
Agba eeko nioya rub
Ita gbangba gbangba
Awo Eko
Lodifafun eeko
Tise omo oloro kan atijo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun eni toda
fayi ifani korubo ki
eni eleni mo bagbe iseere se ifa si ni ki eleyi ko mo yoju
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Agbe bo adie
Eko
Epo
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni todafa yi ifa ni ki elleyi orubo pe awon agba niba elelyi ko rubo ebo meji niyo ru won o kan ikan mole modiesu okan ikan mole nidi esu pelu ori oruko won o pa oruko yi si ori EBO won o gbe ori re le wan owa kan mole midi esu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
oruko
eekan
agbado
eko
epo
opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Otere loun iku ona
Iku ojinan si alarun
Adifafun orunmila
Ti won n ranse iku pe lorun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pere fun renitoda ifayi
ki elelyi orubo laiku ifa ni
eni kan niyi ti arun nse kiwon
orubo fun kiwon o si fi oromo
die kan
kin eba ru oromodie
ni won o fi se Fafun yow a lo
ju si itagbangba ti a sa ti gbe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
akuko adie
eko
epo
opolopo owo
opa aso funfun 6
oromodie kan
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
AWURE
ao toju ewe koko ati iyere ao wa bo igbin apinnu merin ao wa fi se ni epo ni yo ao wa ko obe yin si ori ifa ao wa je ni ojo keji
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao toju ewe segunsete ao toju ekolo ao wa gun mejeji mon ose dudu ao wa fui we fun ojo meta
Explore Ifa
Ofun Ogunda is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ofun Ogunda Odu.
