Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òfún Òdì

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Ofun Odi
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies protection and the need to be cautious in one's actions.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/ofun-odi
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Ofun Odi

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ofundi onso O sika tan onbere Adifafun Orunmila Nijo ti baba n sowo lo si Oja ejigboro mekun Awon ota nin koninde Ebo won ni o se Osi gbebo nibe o rubo Ero po Ero ofa Eba nin laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifanin keleyi orubo nitori aarin ota nin eleyi wa papa julo ibi kan leleyin loyi korubo kole baader keleyi osi man deja koman so wipe iro ninfanpa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ofundi onso Omanratan otunsika Adifafun oningbadi Igba tin be laarin ota Ebo won in ose O si gbebo nibe orubo Ero ipo Ero ofa E bani laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifanin laarin ota leleyi wa eeyan ti o lagbega ni elelyii sugbon awon ota eleyi koje ki eleyi olase yori keleyi osiman fi oju di awo wipe awo kan kere awo ti oba elelyi se gun otare awo kekerenin sugbon kelelyi o man foju di awoo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ofun di raga jigi Adifafun orunmila Baba obori ore La ebo wonin ose O gbebo nibe o rubo Kee pe Kee jinana Ewa banin nin wowore

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa loun pere aje fun eleyi ore eleyi kan ree keleyi obori re ori ore yin in ola eleyi keleyi osi bofa pelu eku eja abodi ekan oti obi ati opolo owo nin eleyi ofi bofa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Eyele kan Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ofun di raga jiji Adifafun folori iranra Ti oran egba ori Ebo won in ose Osi gbebo nibe o rubo Nje ifa loun oraminse Iran ran Ori loun oran minse iran unran

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni keleyi orubo ifa loun pere aje keleyi osi bo orire pelu eye etu kan obi, oti ati owo ifanin eleyi yiola ti oba latan opolopo eeyan nin owo tara eleyi dide

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ako asinrinkan opolopo eeso olowerenjeje opolopo eeso ido eepo obo die odidi atare kan ao jo po a o man fi epo pupa la ti aba fe sun lale lale

Videos

Watch Òfún Òdì teachings on our channel.

Explore Ifa

Òfún Òdì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Ofun Odi. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Òfún Ogbè, Òfún Òyèkù, Òfún Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òfún Òdì Odu.