Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Ofun Odi

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Ofun Odi
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu signifies protection and the need to be cautious in one's actions.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/ofun-odi
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Ofun Odi

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ofundi onso
O sika tan onbere
Adifafun Orunmila
Nijo ti baba n sowo lo si Oja ejigboro mekun
Awon ota nin koninde

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifanin keleyi orubo nitori aarin ota nin eleyi wa
papa julo ibi kan leleyin loyi
korubo kole baader
keleyi osi man deja
koman so wipe iro ninfanpa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ofundi onso
Omanratan otunsika
Adifafun oningbadi
Igba tin be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

ifanin laarin ota leleyi wa
eeyan ti o lagbega ni elelyii
sugbon awon ota eleyi koje ki
eleyi olase yori
keleyi osiman fi oju di
awo wipe awo kan kere
awo ti oba elelyi se gun otare
awo kekerenin
sugbon kelelyi o man foju di awoo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Ofun di raga jigi
Adifafun orunmila
Baba obori ore
La ebo wonin ose
O gbebo nibe o rubo
Kee pe
Kee jinana
Ewa banin nin wowore

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa loun pere aje fun eleyi
ore eleyi kan ree
keleyi obori re
ori ore yin in ola eleyi
keleyi osi bofa pelu
eku eja abodi ekan
oti obi ati opolo owo
nin eleyi ofi bofa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Eyele kan
Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ofun di raga jiji
Adifafun folori iranra
Ti oran egba ori

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni keleyi orubo
ifa loun pere aje
keleyi osi bo orire
pelu eye etu kan
obi, oti ati owo
ifanin eleyi yiola ti oba latan
opolopo eeyan nin owo tara eleyi
dide

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo
Eko
Agbado
Owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ako asinrinkan
opolopo eeso olowerenjeje
opolopo eeso ido
eepo obo die
odidi atare kan
ao jo po a o man fi epo pupa la
ti aba fe sun lale lale

Videos

Watch Ofun Odi teachings on our channel.

Explore Ifa

Ofun Odi is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Ofun Odi. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Meji, Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ofun Odi Odu.