O
Ofun Meji in Ifa Divination symbolizes clarity, wisdom, and the power of divine enlightenment.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Onaa gbororo lejo fi gun agbon
Adifafun orangun
Nijo ti won n pe lalade orun
Ebo ni won ni kose
O gbebo ni be orubo
Nje orangun o wa mon o
A ti ti morangun le
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa nipe ohun pe ire laiku fi eleyi orubo emi re ko si fi ejo kun ebo run ko si mu oti ni ojo tio ba da ifa yii daradara
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko Adire meji
Ori Ejo
Oti
Obi
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Eruku tororo
Eruku tarara
Adifa fun eji orangun
Nijo ti sawo lo ile ilesan
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nibe orubo
Nje igba eji orangun
Sawo dele ilesan ladalaje
Eruku tororo o
Eruku tarara
Igba eji orangun sawo dele ilesan
Lado ni re gbogbo
Eruku tororo
Eruku tarara
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ohun pe ire gbogbo fun eleyi pe ibikan ni eleyi loyin koru bo kole ba ri re mu bo ni be kio si lobo ifa pelu eran ewure.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Adeyeri
Lawo alajiki
Ade tuntun
Lawo aji feran rere lo
Adifa fun orunmila
Ni jo ti lole gbaye tuntun ni yawo
Ebo ni won ni ko se
Osigbebo ni be orubo
Nje erigin alo logbaye tuntun ni yawo aye fa tuntun ojomi lo.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ohun pe ire aya fun eleyi pe oju aya ni pon eleyi ebo ni ko se ko le ba di alaya kio si fi eku eja abodie bo ifa.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku kan
Eja kan
Abodire kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Bagbon osoro
Atidi bole
Ida soro teku bako
Bi alamu osoro
Atidi bo eba ogiri
Adifa fun korowo ti nbe laarin ota
Ebo ni won ni ko se
Osigbebo ni be orubo
Nje obalade toju ota bomi
Osuru suru
Obalade toju ota bomi
Osuru suru
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ohun pe ire isegun fun eleyi ki eleyin orubo isegun tio si lo bo ifa pelu eran elede odidi kan ti won ba fe pa elede yii won yio tori re boo mi ki won oto pa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Odidi elede kan
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao mu eweeyin olobe die pelu iyere ao fi se adire meje tobaje obinrin mesan toba je okunrin kia toje obe ni odi igba ti owo bapa tese pa la le ni ao toje obe naa ao wa so gbogbo obe naa.
ISEGUN
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ao mu eran elede ao toju agbon ile kana o toju ako alangba kana o wa jo gbo gbore papo mon ewe apada ao wa po mon ose dudu eni naa yio mon fi we laro laro.
Explore Ifa
Ofun Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Òfún Ogbè, Òfún Òyèkù, Òfún Iwòrì, Òfún Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Ofun Meji Odu.
