Àjẹ Àkọlé àwòrán Àwọn àyíká Àwọn ojúewé wọ̀nyí jápọ̀ mọ́ Orisa
Ṣafikun Iṣẹ Fún Ìrántí Ikú Ṣẹ́ Ìyíká Ṣiṣeto Aaye
AD

Àwọn ojúewé wọ̀nyí jápọ̀ mọ́ Odu:

Ìkìlọ̀ nípa àyíká fún gbogbo òpópónà Odu.

Fún Àwọn Tó Ń Gbọ́ Èrò Rẹ
O

Ofun Meji

Odu Ifa Ẹsẹ Mímọ́ àti Ọgbọ́n Ìwúlò
Odu Ifa BODE Oracle 2 Èdè Àpẹẹrẹ Mímọ́
Ofun Meji nínú Ifa Divination ṣàpẹẹrẹ ìjìnlẹ̀ òye, ọgbọ́n àti agbára ìmọ̀ Ọlọ́run.
Fetí sí mi
Àwọn ojúewé wọ̀nyí jápọ̀ mọ́: A ṣe àtúnṣe ní April 9, 2026 epilda.com/odu/ofun-meji
Ka nínú: Èdè Yorùbá Èdè Spanish èdè gẹ̀ẹ́sì Èdè Português Èdè Faransé
Odu Ifa Àpẹẹrẹ Ìfọkànsìn Mímọ́

Àwọn àmì Odu mímọ́ tí wọ́n gbé sára àwo ìsọfúnni tó ń jẹ́ Ópele tàbí Ikin

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese Yoruba Ẹsẹ

Onaa gbororo let fi gun agbon Adifafun orangun Nijo ti won n pe lalade orun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nipe ohun pe ire laiku fi eleyi orubo emi re ko si fi ejo kun ebo run ko si mu oti ni ojo tio ba da ifa yii daradara

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko Adire meji Ori Ejo Oti Obi Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Eruku tororo Eruku tarara Adifa fun eji orangun Nijo ti sawo lo ile ilesan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire gbogbo fun eleyi pe ibikan ni eleyi loyin koru bo kole ba ri re mu bo ni be kio si lobo ifa pelu eran ewure.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Adeyeri Lawo alajiki Ade tuntun Lawo aji feran rere lo Adifa funorunmilaNi jo ti lole gbaye tuntun ni yawo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire aya fun eleyi pe oju aya ni pon eleyi ebo ni ko se ko le ba di alaya kio si fi eku eja abodie bo ifa.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan Eja kan Abodire kan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Bagbon osoro Atidi bole Ida soro teku bako Bi alamu osoro Atidi bo eba ogiri Adifa fun korowo ti nbe laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire isegun fun eleyi ki eleyin orubo isegun tio si lo bo ifa pelu eran elede odidi kan ti won ba fe pa elede yii won yio tori re boo mi ki won oto pa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Odidi elede kan Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao mu eweeyin olobe die pelu iyere ao fi se adire meje tobaje obinrin mesan toba je okunrin kia toje obe ni odi igba ti owo bapa tese pa la le ni ao toje obe naa ao wa so gbogbo obe naa. ISEGUN

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao mu eran elede ao toju agbon ile kana o toju ako alangba kana o wa jo gbo gbore papo mon ewe apada ao wa po mon ose dudu eni naa yio mon fi we laro laro.

Videos

Watch Ofun Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Ofun Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include:Ofun Ogbe,Ofun Oyeku,Ofun Iwori,Ofun Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ofun Meji Odu.