Ò
This Odu highlights the need for balance and harmony.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Otua di
Kanhin kanhin di
Adifafun ehoro
Tii se ore ala
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Ero ipo
Ero ofa
Eyin o rifa awo ki bi tin se.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi ifani ore re kan yi ko year fun ore naa ko ma ba fa le aye lo. Ifa ni awon kan nso lati mun. Ifa ni ipase orere ni won fegba mun korubo ko si yera fun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Ojumomo aladi ni o nan ja oorun
Adifafun nini
Omo ere lapa
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, e mapa
Eran abohun ni
Eyan topojola
A ba ojolarin.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi. Ifa ni korubo ija araye ko si rubo ki owo o leje fun asore kan nbe mola mola lori ko firu ebo ni o.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Aso mola mola
Opolopo owo
Abo adie
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Otuadi Kanhindi
Adifafun benbe
Ti n gbogun lo ile liki
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Nje benbe a ni oun sebo
Otuadi kanhindi.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi ko rubo iyii, ifa ni ibi kan leleyi nlo korubo ko le ba gba yi nibe korubo isegun ota
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko
Eye Etu
Igbin
Eyele
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Opara osun ni yake
Adifafun orunmila
Tori tin talogbere ki
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Nje owo mitewe olajuwere temi
Bori awo baju were ajana
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni toda ifayi ki eleyi o rubo ifani oun ti eleyi da si o tidamundamun loree o ti was u ifani korubo ki ara o le baro
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Agbeboadie
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe olajuwere ori okete ao gun pomo ose ao fi iyerosowu te odure ni otua do ao pe ifa si ao po mo ose ao ma fiwe larolaro
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Opolopo ekolo abo adie funfun kana o pa adie yi si orifa gbogbo iye re sinu odo ao wa la inu adie yi ao ko gbogbo unkan inure sinu odoo epo obo ao ko si ekoloyi ao ko sinu odoo ao gun gbogbo re pomo ose dudu ose pupa ose funfun ao ko ose yi sinu ikefunfun ao mo we ao wa fi adie yi pa ese fun awon iya mi ao wa bere ibi ti won o ti gba ao wag be lo fun won.
Explore Ifa
Òdì Òtúrá is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Odi Meji, Òdì Ogbè, Òdì Òyèkù, Òdì Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òdì Òtúrá Odu.
