Read This Odu in Other Languages
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
Ese — Yoruba Verse
Nje ire gbobgo poro ni bode
Ni bode ni ile aje
Ore gbogbo poro ni bode
Ni bode ni le iregbogbo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko kan
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Itaruku lawo itaruku
Adifafun igba
Ti n sawo rode oyo
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Ewa
Isu
Oruko kan
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Adifa fun idin ati igogo
Ni ojo tiwon lole kan rile omo ni bibi
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eko
Obi
Ese — Yoruba Verse
Korodan le okun kori bi agbara ebi se dawon
Adifa fun asake omo ogun
Abu fun arumon omo ija
Adifafun odi naa ti somon bibi inu agbonmeregun
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Epo
Eku
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Explore Ifa
Odi Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
This Odu is also known as: Odinmeji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.
Odus that share the same family or pairing include: Odi Ogbe, Odi Oyeku, Odi Iwori, Odi Irosun.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Odi Meji Odu.
