Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Odi Meji

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Odinmeji
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Odi Meji represents a time of overcoming great challenges with strength and resilience.
Listen
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/odi-meji
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Odinmeji

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Odinmejeji loto lowa re joko adifafun Onibode ajegbere mogun Igba ti momi ojusogbere ire gbobgo Ebo ni won ni kose O si gbebo orubo Nje ire gbobgo poro ni bode Ni bode ni ile aje Ore gbogbo poro ni bode Ni bode ni le iregbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii orubo nitori ire gbogbo pe oju ire gbogboni pon eleyin ebo ire gbogbo ni koru

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye Meji Akuko kan Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Itaruku lawo itaruku Itaruku lawo itaruku Adifafun igba Ti n sawo rode oyo Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe orubo Nje igba oyo nile o Igba emi lowa de ni oko.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nipe ki eleyin orubo pe ire fun lopo lopo awon gbogbo ohun fi eleyin bafe ko mon se komo bere lowo ifa ki ire olede fun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbado Ewa Isu Oruko kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Asahunkulu monkulu moyin baba Adifa fun idin ati igogo Ni ojo tiwon lole kan rile omo ni bibi Ebo ni won ni ki won ose Won si gbebo nibe won rubo Nje, ewole ayo e womo A kii bale ayo laikun E wo le ayo ewo mo.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifani ohun pe ire omo fun eleyin pe oju omo ni pon eleyii pe koru boo mo kio si monk o egbin kole ba biwon.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aran elede odidi kan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Kakole biri koto foosa boosa ogba bi orisa Ogba kore gbe ree sake Korodan le okun kori bi agbara ebi se dawon Adifa fun asake omo ogun Abu fun arumon omo ija Adifafun odi naa ti somon bibi inu agbonmeregun Ebo ni won ni ki won ose Won gbebo nibe won rubo Nje odi naa di naa ibi obati naa man kun Kodinaa maru odi naa di naa bi.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki deyin orubo emi re pee mi re yio gbe ebo ni koge daradara.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aran Agbo kan Epo Eku Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao foju agbado ati okababa ati ewa ati ewe ato ao wa jo po ao wa won fi fo eko mun tabi ka fi oyin lo. ISEGUN

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ewe imon ewe apada ewe dandan ao gun meteta po mon ose dudu ao mon fi we fun ojo mesan tobaje okunrin tobaje obinrin ojo meje ni yio fi we.

Videos

Watch Odi Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Odi Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Odinmeji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Òdì Ogbè, Òdì Òyèkù, Òdì Iwòrì, Òdì Íròsùn.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Odi Meji Odu.