Ò
This Odu emphasizes the importance of resilience and strength.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Okanran dindin
Adifafun olokan ran
Nijo ti n lole Idin lodun wo ebo
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo ni be orubo
Nje ero po
Ero ofa
Ewa bani ni larusegun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki elelyi orubo isegun
pe ogun kan ni owole to eleyi
EBO ni kose kola ba segun
kio si lo fi ewure kan bo
ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Tubuniyanrin
Kere niyangin
Adifafun owu eyin ti somo alagbede
Won ni korubo nilaiku arare
EBO ni kose
Osigbebo ni be orubo
Nje ojojo ki sowu owu alagbede
Ifa mimon je ya ojemi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa sope ki elelyi orubo ajinde
ko si lobo ogun agede pelu
eyele meji kio si fi akuko adire meji rubo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meji
Eyele meji
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Okanni koro sekeseke lebu
Ese kan ni kojoko ginringinrin jana
Adifafun olokanran
Eyi tii se omo iya idin
Igba ti won moni oju sogbere aje
Ebo ni won ni kiwon ose
Won gbebo ni be won rubo
Nje ewo olokanran ewo idin
Ayaye egbon ayeye aburo
Ewo olokanran ewo idin
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pe ire fun omo iya meji kiwon orubo ola kiwon ole ba la ki won osilo fi ewure bo ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Okanran dihundihun
Mosebo apa eran gbingbo
Adifafun dindin nijo ti sawo
Rode oyo
Ebo ni won ni kose
Osigbebo ni be orubo
Nje mosebo akanran dihundihun
Mose boa pa eran gbongbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa sope oun pe ire iyin fun eleyi pe ibikan ni elelyi loyin ebo ni kose ko leba ni yin loun kio si lota onilu lore
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meji
Epo
Eko
Obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ao toju awo ilu pelu ewe
anu ao wa gun po mon
ose dudu ao wa fi omi
agbon po ao wa mon fiwe
larolaro
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao ju eya ogun tise oku
ta toba ya kuro lara eyin
ti won mon fi lu irin legbede
ni ao mu pelu ewe segun sete ao wa lopo ao wad a sinu epo pupa ao wa mon la lalale
Explore Ifa
Òdì Òkánràn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Odi Meji, Òdì Ogbè, Òdì Òyèkù, Òdì Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òdì Òkánràn Odu.
