Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Odi Iwori

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of perseverance and determination.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/odi-iwori
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ogede ni soworoko woroko
Adifafun lanisa
Eyi ti se ore oyinbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eleyi o lobo egungun nitori omo ki oni opolopo atori si idi egungun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbeboadie meji
Pelu eyele
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

BindinBidin
Idin iwori
Adia fun ohun monye
Omo ani kan tuledo
Igba ti n momi oju sogbere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyiii o mon je ki ebi o mon pa oun ki oto mon jeun ki o mon jeun ni asiko

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo ounje
Akuko adie meji
Eyele meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Idin gbagba laberin
Iwori gbagba labefun
Adikaro lorun aladodo
Aladodo owo
Adikaro osokale
Adifafun oloko jobi
Nijo tilole bawon nanja ojogboromekun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki omo iya meji o fi ife barawon se papo ki gbogbo nkan ti won ba dawo le ko le se si dada

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

eeyele merin
akuko adie merin
epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Idin gbagba laberin
Iworin gbagba labefon
Elemonpe lawo inu oko
Aguntanla abori borogindin bo
Adifafun odin ela
Tii se omo bibi inu agbon niregun
Nje odin ela loni ki n wa be o
Bara pefun
Omo iyan kinkinni ori odo
Odin ela loni ki wa be o
Barapetu ope ko monmon se kebe
Omo ejo ko lagbalagba wosa
Odun ela loni ki wa be o o
Bara pe fun ope komonmon sekebe

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN
Ewe segunsete pelu eeru Alamo ao gun papo mon ose dudu ao mon we ni osan ni dede agogo kan osan

Videos

Watch Odi Iwori teachings on our channel.

Explore Ifa

Odi Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Odi Meji, Odi Ogbe, Odi Oyeku, Odi Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Odi Iwori Odu.