Ò
This Odu emphasizes the importance of perseverance and determination.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni patie tere
Ni mun egungun wogbo
Atori agbadagi ni min oro
Wo igbale
Adifafun osu hunlaya
Ti se aya agboniregun
Igabti nmomi oju sogbere omo
Ebo ni won ni kose
O si gbebo nibe orubo
Ero opo
Ero ofa
Ewa bani laarin omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni eleyi o lobo egungun nitori omo ki oni opolopo atori si idi egungun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbeboadie meji
Pelu eyele
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni oju mon on
No gbo poroporo odo
Aajin jin no gbo
Woyo woyo konoso
Afai mon kawo ko mon sun lebi
Adifafun iwori ti n lowo odi nisoju ebi
Ebo ni won ni ko se
Ero ipo
Ero ofa
Iwori ti se wodi nsoju ebi
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyiii o mon je ki ebi o mon pa oun ki oto mon jeun ki o mon jeun ni asiko
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo ounje
Akuko adie meji
Eyele meji
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni bai laselu
Ilu iba dun
Bai laselu
Ilu iba yun
Adifafun iwori ti n lo wo idin
Ebo ni won ni kose
O si gbebo nibe orubo
Nje, bai laselu ilu ibadun
Bai laselu ilu ibayun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki omo iya meji o fi ife barawon se papo ki gbogbo nkan ti won ba dawo le ko le se si dada
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eeyele merin
akuko adie merin
epo ati eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ewe segunsete pelu eeru Alamo ao gun papo mon ose dudu ao mon we ni osan ni dede agogo kan osan
Explore Ifa
Òdì Iwòrì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Odi Meji, Òdì Ogbè, Òdì Òyèkù, Òdì Íròsùn.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òdì Iwòrì Odu.
