Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òdì Ogbè

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Idingbe
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of overcoming obstacles through wisdom and perseverance.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/odi-ogbe
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Idingbe

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Gindanginda lalulu ogindigbo Adifafu oju abufu aye ti won saya olofin Awon lose fafun Olofin Nijo ti won ni korubo Ki oju ati aye omo n banun O si gbebo nibe Orubo Nje awa roju o asunraye ari ohun to muni awayo Ao toju sigidi alamon ao wa toju eyin sin Horo ao wa egusin itoro yin ao wa fi se eyin si lenu ao wa mu irun ara oruko ao wa fun si lori ao wa pa eran oruko le lori ao wa logbe sidi esu fun ojo mesan ti o ba di ojo kesan ao wa bi ifa bi abati se boya arin monle ni o boya alo so sinu igbo ni o.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyi orubo ola kio si rubo ki ore omo banu tori ore kan lofe nu yin ebo ni kose ki ore naa omo banu kio lofi akuko adire kan bo esu

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meta Epo Eko Obi.
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ogunijimogbe awo ni Adifa fun Oruminla Baba da idingbe Won ni ikude Ebo ni o se O si gbebo nibe orubo Nje, Ogere ji mogbe awo ni Awo ki da idi n gbe kawo oku mo Ogere ji mogbe awo ni.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa sope ohun pere laiku fu eleyin Ki eleyin orubo eemi re ki won o si se fabe fun ki si fi oru Ko rubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran oruko kan Sigidi Epo Eko Obi.
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Musa awo awusa Awa awo ode ejigbo Ogere ti mogbe awo won lode ido Adifa fun won lode ido Nijo aye won lekoko Ebo ni won ni kiwon ose Won sigbebo ni be won rubo Nje, eyin omewo E peran tan edeje sindigbe loju

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire isegun fun eleyi pe ikan eleyin ledie ebo ni kose kosi sora fu ikan ewo idile won ki osi mu fi ikan eleje runbo ti ifa bamu ebo sibe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo owo Epo, Eko Obi -452120-199390
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Idingbere ariunaa ko Adifa fun Lajubola Ti yio soko arugbo Ebo ni won ni kose O gbebo ni be orubo Nje, oba tete farugbo Koraye bimon

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ape ohun pe ire aya fu eleyin pe oju aya nipon eleyin fun gbo ti obe fefe aya eni toju lo niko fe kole ba tete bi mu kio si lobo ifa ape ilu eku eja abidie

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan Eja kan Abode kan Epo Eko Obi.

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju ewe anu ao wa lopo mon ata ijosin ao wa fi se eyin adire merin je lepo niyo eni naa yio je obe yi pelu adura gbogbo ohun ti o ba fe.

Videos

Watch Òdì Ogbè teachings on our channel.

Explore Ifa

Òdì Ogbè is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Idingbe. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Odi Meji, Òdì Òyèkù, Òdì Iwòrì, Òdì Íròsùn.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òdì Ogbè Odu.