Feed Orisa Circles Pages Blog
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
O

Odi Ofun

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of wisdom and insight.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/odi-ofun
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

ESE KIN NI
Idin funfun ni koniran
Funro funfun ni ko labo
Adifafun aje
Aje n lo igbe loo do si
Adifafun omo araye
Nijo ti won n mu omi oju sogbere aje

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa sope oun pe ire aje fun eleyii, ki eleyii o le ba a ri aje jeun ki o si lo fi eye etu ati ekuru ati eyin ogede bo aje

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu
Eyin
Ogede
Ekuru
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Idin funfun ladide
Adifafun kanhin kanhin
Eyi tii se omokunrin odede
Igba ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ire isegun fun eleyii, ki eleyii o rubo ko le baa segun ki o fi abere kan kun ebo ru pelu akuko adire meji
If ape ire fun eni to da ifa yii, ifa ni eleyi ko kojumo oun ifa, omo ifa leleyi latorun wa ki gbogbo oun to n ba dawo le kole baja sayo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meji
Opolopo abere
epo
Eko
Obi
Akoru akuko
Eyele
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Idin funfun koniran
Funro funfun kolebo
Afeniyan ti ko ba fi tie gbole
Adifafun oye ti n sawo rele igbeti

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa oun pere gbogbo fun eleyii ki eleyii o rubo pe ibi kan ni eleyii lo yii, ko rubo ki o lo le e ba di eni nla lohun.
Ifa pere fun enito da ifa yii korubo nitori ogun ifa ni oun loun o gba kale ti ogun ko fi ni mu ko bo fa leku leja lobi die pelu obi, oti.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie kan
Opolopo ata pupa
Opolopo eru
Epo
Eko
Obi
Abo adie
Eku
Eja
Obi
Oti
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Idin funfun gbo
Adifafun orisa nla oseremogbo
Nigba ti n lo oko ailero lodun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pe ire okere fun eleyii, ki o si lo bo orisa pelu opolopo igbin, ki o si fi eku, eja, abo adire bofa.
Ifa pere fun eni toda ifayi korubo ki aje o le ba to lowo ifa ni oju aye nip on eleyi pe yo la yosi fi aje da ewu sara

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan
Eja kan
Abo adie kan
Opolopo igbin
Epo
Eko
Obi
Eyele
Opolopo owo eyo
Iko owu
Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

WEALTH
Uno obtendra egbo agbon con ijosi pimineta, y uselo para cocinar dieciseis trozos de carne de una vaca con aceite de palma y sal y que no se debe usar agua en el proceso excepto el agua de coco y comer la sopa.
VICTORY
Uno sacara la arena con el pimiento de caiman y los triturara y usara para hacer once incisiones en el centro de la cabeza y en los dos tobillos y tomara el resto con aceite de palma.
IROSUN AGBE
ESE IFA
Ororomoro Awo ile orunmila
Adifafun orunmila
Baba n sawo lo ile liki
Baba n sawo lo ile gbanja
Ebo won ni kose
O si gbebo nibe o rubo
Fun o ororomoro
Ikin iwo ni mo n ro fun
Aya, omo, ire gbogbo ni o ni lowo
Ifa mo wa ro fun o
Oromoro
Ikin iwo ni mo n ro fun
Ifa ni oun pe ire fun eni toda ifa yii, ifa ni ire gbogb ni n pon eleyi ko ko oro re tofa ko si fi obi bofa
Akoru eyele
Akuko adie
Abo adie
Opolopo owo
Ewe aje toni ina dadaa ewe abamoda mefa iyere a o wa lopo a o fa sinu isaasun tutu a o din bi ata ti won ma fije isu a o wa so kale a o wa da oyin si a o ropo a o wa ko sinu awo funfun a o bo ogede paranta merin sibe eyin merin a o wa je tan pata pata

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ewe ekuya tutu iye igun merindinlogun odidi atare kan a o jo po a o ma fi fo eko tutu mu laro laro.

Videos

Watch Odi Ofun teachings on our channel.

Explore Ifa

Odi Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Odi Meji, Odi Ogbe, Odi Oyeku, Odi Iwori.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Odi Ofun Odu.