Ò
This Odu represents the need for adaptability and resourcefulness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE KINI 1
Kala nkan di
Adi kaka wolu
Adifafun orunmila
Baba ngbogun lo si ibi atoketodoke
Ebo ni won ni ko mon so
Osi gbebo nbe orubo
Ona e pe
Ona eejin
Ewe bawa laruse ogun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ibi ti eleyi nlo yi if ape ogun nbe nibe fun ifa pe korubo lo kole ba segun bo ibe
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko
Akuko adie meta
Agbebo adie meji
Eku
Eja
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ika dindi awo erin
Adifafun erin
Ika dindi awo efon
Adifafun efon
Awon ko niyi ebo
Igbati won sunkun pe awon ko niyi
Ebo ni won ni ki won ose
Won si gbebo nibe won rubo
Nje erin lola o
Efon niyi
Ebo wa di ebo aruda
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki awon omo iyameji tabi ore meji ko rubo ki won o le ba gbayi nibi ti won ban lo tabi lori nkan ti won ba dawo le
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele merin
Pepeye merin
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni akadi akadi
Adikaka wolu ntori ogun ologun
Nijo ti n lo le ba won jagun igbo
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Kee pe
Kee jina
Eba ni laruse ogun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi orubo oun ti o fe dawole ki ole ba se aseyori re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie merin
Eye etu merin
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Agborin o ni gege
Awo ile orunmila
Adifafun orunmila
Ifa nsunkun pe oun ko lowo lowo
Ebo naje ni won ni ko mon se
Osi gbebo nbe orubo
Ifa wi olodi owindinwindin
Ire aje waje de tuturu
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ki eleyi o bo aje if ape eleyi nsunkun aje aje o joko ti eleyi to
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meji fun aje
Igbin merin fun aje
Obi
Oti
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
1ISEGUN
Eeso lowerenjeje eyo meje ao lo pelu eyo atare meje ao lo ti o kunna dada ao wate ni ikadi ao so gbogbo nkan ti aba fe ao wa fi sin gbere si orikerike ara
Explore Ifa
Òdì Íká is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Odi Meji, Òdì Ogbè, Òdì Òyèkù, Òdì Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Òdì Íká Odu.
