Í
This Odu represents the need for balance and harmony to achieve success.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Ejemu ni difa ori igi
Akan ni teye tutu
Adifafun Lanrubo
Ti n somo ajaniwarun
Igba tin raye alainiku e
Ebo ni won ni ko se
O si gbebo o rubo
Nje ndi ndi ibo ni koje ki lonnibo
Ko baku lo ndi ndi bo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire fun eni to da ifa yi won orubo aiku fun omo to dibo ifa yii tabi ifa oun pere aiku fun eni to da ifayi ko lo fi akuko die bo ibo ifa ti won da.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Itakuta lanta aso irikuri laari ofii
Adifafun igbin
Ti n lo re wo ilero isu tuntun lodun
Won ni ko rubo saiku arare
O gbebe nibe orubo
Nje eyin n isoro ope
Aweku lefe wegbin ndahun.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa loun pere aiku fun eleyi ko lo re te ifa ki see ati osi arare ko le ba kuro.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Ota kinni sokin
Arosunta kelekun
Adifafun orunmila
Baba o ta kedeyofidi akapore loju
Yoo ni oun o marun ti n se oun
Ebo ni won ni o se
O si gbebo nibe orubo
Keepe
Kee jinan
E wa ba ni jebutu ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to da ifayi ko rubo ki ifa o maa ba se pada leyin re kio sib o fa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Akuko
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
ASE IFA
Isale akitan ni roganje ganje
Adifafun jegbe
Omo ajegba rinmokun
Ebo ni won ni ose
O gbebo nibe orubo
Ruru ebo
Eru atuka esu
E wa bani laiku gbanhin gbanhin
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to dafa ifa korubo ifa oun pe aiku fun ko toju ipepe irun fi kun ebo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko
Adire
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe tangiri (60) agun papo mo ose owo eyo ti ko loju (60) ao lo aopapo mo ose tia ba guntan a o wa pa eyele kan si a o ro eje re si ao po mo ao la eyele yi laya ao fi tele igba ao lko ose yi le ao fi ori eyele yi gun ose lori ojo aje lase ifayi ojo aje lao bere si ni we
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ipose adire, ipose eyele a o jo papo mo atare odidi kan a o fi ssin gbere yipo orun owo mejeji
Explore Ifa
Íròsùn Òyèkù is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Iwòrì, Íròsùn Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Íròsùn Òyèkù Odu.
