Í
This Odu represents the need for cleansing and renewal.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Adako pebu apajuba kan odo
Adifafun ajibola tii se ore aroni
Igba ti n be laarin ota
Ebo won ni o se
O si gbebo ni be o rubo
Nje aroni o seun
Aroni iwo ko seniyan o
Se je kebo odo felebo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa sope ota fun eleyi ko rubo ko bale segun won ore kan wa fun eleyi peota nikorubo ko le sugun won
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Egungun ileyi oso
Eniyan be kiki ika
Adifafun ofaafa
Tiyo ye eyin tie sarin igbe
Ebo aye ni won ni kose
O si gbebo nibe orubo
Nje ofaafa kiko la ko eyin re akorijo
Ero ipo
Ero ofa
E wa bani laru segun
Arusegun labami lese ope
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyi ko rubo fun aye awon nda lamu won o jinna si korubo kole ba segun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire
Pelu opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Eegungun ileyi kiki oso
Osa ileyi kiki aje
Adifafun otosi odo
Ti o mo singba lorun
Yoo mo gbade bori
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje otosi ado sin lorun hingbeyin borun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to da yi ko si rubo gbese, ifa ni eleyi jegbese ko si rubo kolebo kole baje gbe kosi rubo ola
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Akuko adire
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Agbara ni o gbaya iun ogan baje
Adifafun abo ifa bole nitori omo
Ebo won ni ose
O si gbebo nibe orubo
Nje mobo fabole
Mo rire
Mobofa bole lolami
Mobofa bole morire
Kee pe
Kee jinna
E wa bani ni jebutu ire
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni todayi ifa ni oju omo nip on eleyi korubo ko sib o ifa ati ile
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abodie
Opolopo ekuru
Opolopo eko
Oti
Opolopo obi
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Odidi lekeleke kan ori eye kan ori agbigbo kana o jo po ao po mo ose ao ko siunawo funfun ao ma fiwe ni afejumo laisoro si eni kan kan
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Egbo ologunsese egbo ipin ao jo po mo odiid atare kan ao fi sin gbere si arin ori meje ni ao sin
Explore Ifa
Íròsùn Òsé is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Íròsùn Òsé Odu.
