Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Í

Íròsùn Ósà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the importance of vigilance and awareness.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irosun-osa
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Pasan wara Adifafun won nirosun omosa Igba ti fomi oju sogbere ire gbogbo Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ani baba loni o Ani pasan wara Ani baba

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa so pe eni to dafa yii pe eegun kan wa nidile won ti won ti pati, pe ki o lo ree gbe eegun yii jade, ki won le baa ni aseyori, ki won o fi opolopo akara ati olele pelu eko bo eegun na

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo pasan Olele Akara Eko Oruko Akuko adie Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Sokoto makin Sokoto makin Efin logori eja lokeriri kebekebe Adifafun atagin ningin Ti n somokunrin aye Igba ti n torun bowaye Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje, ifa wo lo mo Mato enikan o mo eyi to ba to ni jeer

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eleyii fe dawoo lenka, ko rubo kin nkan naa ko le baa ja sayo, to ba je pe eleyii fe lo sibi kan ni, ko rubo koto le kinrin ajo naa ko lo so eso rere ki o bo ifa ko to lo.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku Eja Ewure Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Irosun sara gaga kanle Oba tojupo po wol ile Adifafun gbedako Tii se aremo ogun Igba ti raye lainniku Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Keepe Kee jinna E wa bani laiku kangiri

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pe ire fun eni to dafa yii, ifa ni oun ri ire aiku fun, ifa ni ko rubo fun omo re kan nitori iku, ko si boo gun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Olosunsa aoro olosun O sa ao ro tepolosoro leje o soro Adifafun otupata Tii se aya agboniregun Ebo ni won ni o se O si gbebo nibe o rubo Nje, otupomawa o Awo eji o munwa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pere fun eni toda ifa yii, ifa ni ki iya eleyii ko mota epo pupa to ba je pe obinrin komo ta epo ko si mun nire kofi pa ese fun awon iyami

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire Eyele Opolopo owo

Videos

Watch Íròsùn Ósà teachings on our channel.

Explore Ifa

Íròsùn Ósà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Íròsùn Ósà Odu.