Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Í

Íròsùn Òkánràn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the importance of resilience and strength.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irosun-okanran
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Irosun abeyin kanran kanran Adifa fun oletapa Eyi ti nse omokunrin ogodo Nijo ti ori ogodo gba obi mefa Nitori omo titun Ebo won ni ki ose O si gbebo nibe orubo A mu meji afi rubo oko Amu meji afibo esin Amu meji yoku afibo ori esin nitori omo titun Nje olu ogodo pele Omo amu obi kan mu bo igba eegungun Ero ipo Ero ofa Ifa komo leyin ode yoyo.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pere fun eni toda ifayi ni kobo ori re pelu obi kire ole ba to lowo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Irosun keyinda awo akin oyin Adifa fun akin oyin Igba ti n fomi oju so gbere omo bibi surusun Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe orubo Kee pe Kee jina E wa ba ni ni jebutu omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe oun pe ire fun eni toda ifa yi ifa sope kiwon o kiesi alaboyu kan nibeyen oyun towa ninure ki won o rubo fun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Ewure ni wom yoo fi paro omo to febi Opolopo eyele Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Eesun lote koko janan Oun reti apon riri gangan Adifafun atoye bi tiise omoyeye ega Ti n nira kaka alaile dide Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe orubo Nje birosun keyinda Eyin o roju atoyebi topon koko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa loun pere fun eni toda ifayi ilorubo nitori arun oju ifani toba pe saa oju eleyi yo mo pon korubo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko die Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

ESE IFA Kanle kanle aran Adifa fun opa Ti yoo pejo ti o poro Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe O rubo Nje opa pejo o poro Eyin o rirosun Bi ti n kanran mo.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa e ki eleyi o rubo isegun ota pe enikan niyi to geju eleyi lo tin ba sota korubo kole ba segun re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie Opolopo owo

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe esisi merindinlogun aolo pomo iyere merindinlogun ao fi se eja abori kanje leponiyo ao se tiyo jina to ba tijina ao wa se adura si ni ihoho aoje ni ihoho

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Eso eyinolobe ewe rerinkomin odidi kan a o jopo ao fi sin gbere kan ni arin ori

Videos

Watch Íròsùn Òkánràn teachings on our channel.

Explore Ifa

Íròsùn Òkánràn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Íròsùn Òkánràn Odu.