I
Irosun Meji speaks to the hidden realms, emphasizing the influence of ancestral spirits in shaping one’s destiny.
Listen
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Adanuko adaroko adanuko
Adarodo akanuko
Ada wa mofa ada wa moro
Adifa fun eleko idere
Eyi ti o lo ree kale le otole
Ebo ni won ni kose
O si gbebo ni be orubo
Nje elekodere sebolo ojere
O roso dudu oroso pupa
O fa poti fidi ole keun ka
Eleko dere sebolo njere
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa niki eleyin orubo pe oju aye nip on eleyin ebo ni korin ki ki won soto mon soto ki ile ole duroti
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku meji
Eja meji
Abodie meji
Eyele kan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ejiroro eyi rosu
Adifa fun alari ohun ododo
Ni ojo ti won raye lainite
Ebo ni won ni kose
Won gbebo nibe won rubo
Nje, aye ye ododo aye ye alari
Ohun gbogbo ni seyeni.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyin orubo iyin pe awon peja kan ki won orubo ki won ole bami lari
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko
Epo
Eko
Obi
Isu
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Eni toto ni gba ni gbami
Adifafun ikodoro
Ni ojo ti lole gba owu
Ebo ni won ni kose
O si gbe boni be orubo
Nje ikodoro
Agbata ni osa gbamini more
ikodoro.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
If ape ire isegun fun eleyin pe ogun kan loka eleyin won ni ebo ni kose ki ogun naa ole ba se fun.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Epo
Eko
Obi
Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Akuluwe ni foso lori yangin
Ojooda arorun ofoso
Adifafun ya wopa
Tii se omo bibi inu agbon meregun
Igba ti won momi oju serahun ire gbogbo
Ebo ni won ni kose
O gbebo ni be orubo
Nje okete nifa gba
E se yaa yawo peran.
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
If ape ire gbogbo fun eleyin, pe o ti se awon asise pe gbogbokan ti se asise won ni be ebo ni ko se kosi be iya dara.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Okete aye kan
Epo
Eko
Obi
Owo.
Explore Ifa
Irosun Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Iwòrì, Íròsùn Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irosun Meji Odu.
