Í
This Odu emphasizes the importance of perseverance and determination.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
Oju odo lodo fi gunyan
Oju awo lawo fi gbobe
Akii foju oloju sowo kajere
Adifa fun Teegbe
Tin somo bi bi inu agbomiregun
Igba ti n torun bo waye
Ebo ni won ni kose
O si gbebo nibe o rubo
Ero ipo
Ero ofa
Ifa kii temo re loju egbe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa loun pe re fun eleyi ko gbobe egbe re dada ifa loun ogbe elelyi keleyi o mun ra si ebo ruru ati ifa egbe wipe iyanju eleyi ko kun to
Ifa ni ki eleyi lo re bo orisa orisa kan wa ni idile awon eleyi ki won gbe orisa na jade ki won o bo dada ( opolopo igbin obi ati oti )
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Aso funfun
Eyele
Eyin
Opolopo owo
Akuko adie
Opolopo igbin
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ahoro ile aboju poki
Adifa fun olomu jugba
Ti n se yeye ere
Igba ti n momi oju sogbere omo
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje, omo tororo momopomoje
Olomujugbala
Abo omo tororo momo pomoje
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to da ifa yi ifa ni oju omo nipon eleyi ifa ni omun eleyi bi tobi ju kan lo ifa ni eleyi bi abiku pe o ifa so pe omun ka omo to ba je korubo ki won o bo omunyan
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Abo adire
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
ESE IFA
O fi tiele gbo teni eleni
Adifa fun emilenige
Tii sawo rode awote
Ebo won ni o se
O si gbebo nibe o rubo
Nje emilengbe o de Arode
Awoye gbogbo la bare nle mode awuro
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to da ifa ko rubo ifa ni ti won pe eleyi ni bi kan ko tete mo debe tori ire ni
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Akuko
Opolopo owo
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Ewe ina ao lopo mo iyere (16)ao fi se edo maalu tia ge simerindinlogun (16)leponiyo ao je ni gbibgo nan
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Awo etu de egun ori ewure ti won fib o ifa ao jo mo odidi atare kan aofi sin gbere si arin ori meta (3) ni ao sin
Explore Ifa
Íròsùn Iwòrì is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Íròsùn Ogbè, Íròsùn Òyèkù, Íròsùn Òdì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Íròsùn Iwòrì Odu.
