Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ì

Ìrètè Òsé

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Irete Ose
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Irete Ose also known as Irete Alaje signifies power, victory and the blessing of great children.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irete-ose
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Ose

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ogbologbo Oya ni yipon eyin Adifafun orunmila Baba n sawo relu ilodi Ebo won nifa ose O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E ba ni laru segun.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ibi kan lele yii nlo yii, ko rubo awon ota po loun, yio si segun won ko gbebo, pe aala oorun ti eleyi sun ko dara rara apeere awon ota ni, won o si fe pa eleyi ni.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Akuko adie kan Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Pa man siki Adifafun boti Ti n gbogun lo ilu ajarun Ebo ni won ni o se O si gbebo nibe orubo Ero ipo Ero ofa E ba ni laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo bi kan leleyi n loyii, ogunpo nibe sugbon keleyi o rubo paa paa julo, won ti fi oogun soju ona fun eleyi, nibi ti eleyi ba gbalo ko maa gbabe bo nitori awon ota ti yan le kalefun.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Opolopo okababa Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Yoo yo biyoyo Yoyo bi yoyo Adifafun won ni rete alaje Nibi won ti n sukun aje suru suru Ebo won ni won o se Won si gbebo nibe won rubo Ero ipo Ero ofa E ba ni bola ba pere gede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo, eleyi n sukun aje, ifa ni ire aje n bo fun eleyi gbogbo oun ti eleyi se kolojutu lenu isere kolojuto keleyi o dimo n ifa, lodo ifa nire aje re wa kosi ma maa safojudi.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado lopo lopo Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ifa see ko awo omode Eniyan atata se mo Awo oke ijero Aimo eeyan atata ka so wipe a o lowo lowo Apata piti oruko ni won fi ma n ni Adifafun won ni rete alaje Nibi ti won ti n wa owo piti piti Ebo won ni won o se Won si rubo Ero ipo Ero ofa E wa ba ni niwowo o re.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo ire aje gidi gidi fun eleyi, ki eleyi o fi elede bofa kara o le defun a je eleyi yio si ma n eeyan Pataki Pataki lara awon eeyan Pataki yii ni eleyi yioti la

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Elede a o fi bofa

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ewe tete ewerinrin odundun ire lapa lapa ewe igba ewe gure a o gbo gbogbore po a o fi we ifa a o pa agbegbo adie bofa ati eku eja omin ti afi wefa yi a o fiwe a o man yo mu.

Videos

Watch Ìrètè Òsé teachings on our channel.

Explore Ifa

Ìrètè Òsé is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Ose. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Ìrètè Ogbè, Ìrètè Òyèkù, Ìrètè Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ìrètè Òsé Odu.