Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ì

Ìrètè Ògundà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Irete Ogunda
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu emphasizes the need for thoughtful decision-making.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irete-ogunda
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Ogunda

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Eworo Isan Eworo atori Adifa fun sango oun ogun Nijo ti won jo n sota Ebo won ni won ose Ogun ni n be leyin ti tubo Ero ipo Ero ofa E bani laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Awon meji kan ni won jo n sota yii, sugbon keleyi orubo yio segun nitori ota eleyi to bi ju lo sugbon yio segun re keleyi o si bo ogun agbede obi ni yoo fi bogun agbede.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Eworo isan Eworo atori Adifa fajiga lorun Tii sobinrin aaye Igba ti n be laarin ota Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E bani laru segun.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Obinrin eleyi ni keleyi o rubo fun ki won ota oman pa ni tori iyawo eleyi ni ota pupo ota ti moun wi yi lati idile obinrin naa ni won ti le wa.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Pankere wobo Wobo pankere Adifa fun enlojo obo Ti n loko ailero lodun Ebo won ni won ose Won si gbebo nibe won rubo Ero ipo Ero ofa E ban in wowo re.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ibikan lawon eleyi n lo, ki won o orubo, ki won o to lo won yoo la bo ibe, won o fi opolopo agbado kun ebo won ru, ki won osi man jara won niyan, ki ire won oman ba fo won ru

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Eyele kan
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Epo lose jesu Suuku lo se nudi Adifa fun orunmila Ifa n sawo rele olokun sani ade Yio wa gba aaya bo Ebo won ni ose Osi rubo Nje ifa gbase lowo wa ariya

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo, ko si se aase onje oti fun awon awo kire aje eleyi ole to lowo, odo eeyan nla kan leleyi n lo yii, yio rire munbo, eni nan tin damu lori ikan re kan, sugbon eleyi ni yio ba soro re dayo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Ao fi opolopo onje obi oti bo ifa

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Egun igbago opolopo isu eminan ikoode kan odidi atare kana o jo po ao man fi epo pupa la lale sun

Videos

Watch Ìrètè Ògundà teachings on our channel.

Explore Ifa

Ìrètè Ògundà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Ogunda. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Ìrètè Ogbè, Ìrètè Òyèkù, Ìrètè Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ìrètè Ògundà Odu.