Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ì

Ìrètè Íká

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ifa Irete Ika
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu signifies the power of transformation and strategic planning.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/irete-ika
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ifa Irete Ika

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Ateka Awo ila Lodifa fun Ila Ateka awo ikan Lodifa fun ikan Adifa fun bobo awodi Nijo tawon mete eta n tode orun bowaye Ebo won ni ki won ose Bobo awodi ni kan ni be leyin tin tubo Kee pe Kee jin an E wa ba ni laru segun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo awon meta ni ki won o man rubo sugbon eyo eni kan ni yio rubo oun ni kan ni yio segun kele yi osi rubo fun omo re kawon ota oman man pa omo ele yii.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Akuko die kan
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ilasa Te Gbegbe ni won Iwo nikan kobe Adifa fun orunmila Baba nbe laarin ota Ebo ni won ni ose O si gbebo nibe orubo Nje, ife afelasa Enikan o mo wipe o lee sola mo Ife afe lasa

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo awon ota n wo eleyi ni wo koku koku sugbon korubo yio segun paa paa julo awon ota ti ro eleyi pin wipe kole jen kan kan laye man sugbon ki eleyi orubo ni soju awon ota nan ni eleyi oti la .

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oku Ita Oberu Okunkun Adifa fajimokun Tii somo oba orangun ode ila Igba ti n fomi oju sogbere ire Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa Aje wa jede turutu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ire aje fun eleyi lenu ise re, ko si man fe bo salo, keleyi o si ma maa sun orire loro mo, kosi ma man febi para re, kosi man se aanu ki re aje re ole baa tete tee lowo .

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Eyele meji
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Oku ita nii oberu okun kun Adifa faje olokun sannin ade Igba ti n tode orun bo waye Ebo won ni ose O gbebo nibe o rubo Nje aje lo ni so Fi so sile min.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Keleyi orubo aje fe joko ti eleyii, ko si man bi nun kire ajere olejoko tii lati ara eleyi opolopo eeyan ni oti arare lai kosi man se oore.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Epo Eko Agbado Owo Eyele meji

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Eyele dudu kan opolo esuru pupa ewe ailu odidi atare kana o jo po ao man fi fo ko mun

Videos

Watch Ìrètè Íká teachings on our channel.

Explore Ifa

Ìrètè Íká is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ifa Irete Ika. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Irete Meji, Ìrètè Ogbè, Ìrètè Òyèkù, Ìrètè Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ìrètè Íká Odu.