Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Í

Íká Òwónrìn

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility in life's journey.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/ika-owonrin
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Araka ajagba Araka ajagba Adifafun akika Ti se omo oloro lese oke Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe o rubo Eni ti o sowo edu Ki mon se iye meji

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe eleyi o mon se iyemeji lori gbogbo nkan ti o ba n se ifa ni okankan ni koni

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meji Eyele meji Obi Oti Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ika wonrin wonrin Wonhun kankan jiwon Adifafun ologbo jigolo Igbati nsunkun pe oun o laje Ko no ni omisin Ebo ni won ni kose O si gbebo nibe o rubo Nje ologbo jigolo Ese tolo ni ominsin

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi orubo ki ole ba di eni apasin ni ibikibi

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meta Eye etu meta Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Araka ajagba Araka ajagba Adifafun opipi Igbati nsunkun pe Oun ori asobodi Ebo ni won ni ko mon se Osi gbebo nibe orubo Kee pe Kee jina E bani ni jebutu ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi o mon fi nkan re toro papa julo aso ara re

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Agbebo adie meji Aso ara eni ti O dafa gangan Akuko adie meji Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ika winrin winrin Babalawo alabahun Lodifafun alabahun Igbati nsawo re abe aka Ebo ni won ni komon se Igba aisebo Igba aise tutu Eyin ori ifa awo ki bitinse

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi o mon deja ko si mon gbon ju ara re lo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Alabahun meji Akuko adie meji Epo Eko

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ewe damonito ao lo ao fi se igbin merin lepo niyo ao si fi igi nla ku obe ao wa se ti ojina dada ao wa lo te ifa ika wonrin ao pe ifa si ao wa se isure si ao lo gbe si idi esu lale gege bi isegun ota

Videos

Watch Íká Òwónrìn teachings on our channel.

Explore Ifa

Íká Òwónrìn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Íká Ogbè, Íká Òyèkù, Íká Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Íká Òwónrìn Odu.