Í
This Odu signifies the power of transformation and the importance of embracing change.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Oturupon ka
Oturuopon ko
Awo ori lose fafun ori
Ori tode orubo waye
Ebo ni won ni kos.e
Osi gbebo ni be orubo
Nje ori kowa gbeni o
Ori apere
ao toju ewe iyeye pelu owo eyo iyere ao wa lopo ao wa fi se eran okete odidi kan lepo niyo ao wa ko obe yin si ori ifa ti obajinaa too ao wa se adurasi ao wa je obe naa gbogbo oun ti abele je ni nu obe yin ao ko si ibikan ao wa mu ewe mejejeji yin ao wa gun papo ao wa po mon ose dudu ao wa on fi we laro laro
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire ola fun elelyi
Ki elelyi orubo ola kio lobo ori
Re pelu eye etu kan kio si lo fi eye eku kan bo fa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu meji
Epo
Eko
obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Oturupon kan pon ko
Adifafun orunmila ni jo ti
Baba momi oju sogbere aje
Ebo ni won kose
Osi gbebo ni be orubo
Eropo
Ero ofa
Ewa bani ni jebutu ire
Gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire gbogbo fun
elelyi ki elleyi orubo ki o si lobo
ifa pelu pepeye kio si fi
oruko rubo fesu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran oruko kan
Pepeye kan
Epo
Eko
Obi
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Oturupon ka
Oturupon ka
Pon ko ponko majalawa
Adifafun omi subu laje omo
Oni gbobu aran
Igba ti momi oju sogbere omo
Ebo ni won ni kosu
Osi gbebo nibe orubo
Nje kini oyele sukupe
Omo loyele sukupe omo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pere omo fun
elelyi pe oju omo nip on
elelyi korubo pelu eran ewure
kan ati ye imu fun ifa
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
Oti
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Oturupon kan pon ko
Ponkoponko ponran ete
Adifafun egbe aye
Abufun torun
Igba ti won tode orun bowaye
Ebo ni won ni ki won ose
Won sigbebo ni be won rubo
Nje egbe aye won talo
Boro kini orun ko ni jetaye
Ote
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pere ire ola fun
eleyi ki eleyi olo bo egbe
orun re pelu gogbo oun
tenu je kio si fi akuko adire meta rubo fesu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire meta
Gbogbo oun ti enuja
Epo
Eko
Obi
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ao toju ewe apada ao toju ewe labelabe ao wa po mon ose dud ao wa lo bin pe agbde ao wa ko ao po mon ose naa ao wa mon fi ose naa we.
Explore Ifa
Íká Òtùrùpòn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Íká Ogbè, Íká Òyèkù, Íká Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Íká Òtùrùpòn Odu.
