Í
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility in life's journey.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Araka ajagba
Araka ajagba
Adifafun akika
Ti se omo oloro lese oke
Ebo ni won ni kose
O si gbebo nibe o rubo
Eni ti o sowo edu
Ki mon se iye meji
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe eleyi o mon se iyemeji lori gbogbo nkan ti o ba n se ifa ni okankan ni koni
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meji
Eyele meji
Obi
Oti
Epo
Eko
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ika wonrin wonrin
Wonhun kankan jiwon
Adifafun ologbo jigolo
Igbati nsunkun pe oun o laje
Ko no ni omisin
Ebo ni won ni kose
O si gbebo nibe o rubo
Nje ologbo jigolo
Ese tolo ni ominsin
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi orubo ki ole ba di eni apasin ni ibikibi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meta
Eye etu meta
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Araka ajagba
Araka ajagba
Adifafun opipi
Igbati nsunkun pe
Oun ori asobodi
Ebo ni won ni ko mon se
Osi gbebo nibe orubo
Kee pe
Kee jina
E bani ni jebutu ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o mon fi nkan re toro papa julo aso ara re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie meji
Aso ara eni ti
O dafa gangan
Akuko adie meji
Epo ati eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ika winrin winrin
Babalawo alabahun
Lodifafun alabahun
Igbati nsawo re abe aka
Ebo ni won ni komon se
Igba aisebo
Igba aise tutu
Eyin ori ifa awo ki bitinse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o mon deja ko si mon gbon ju ara re lo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Alabahun meji
Akuko adie meji
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ewe damonito ao lo ao fi se igbin merin lepo niyo ao si fi igi nla ku obe ao wa se ti ojina dada ao wa lo te ifa ika wonrin ao pe ifa si ao wa se isure si ao lo gbe si idi esu lale gege bi isegun ota
Explore Ifa
Íká Òwónrìn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Íká Ogbè, Íká Òyèkù, Íká Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Íká Òwónrìn Odu.
