Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
I

Ika Meji

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ikameji
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Ika Meji in Ifa Divination symbolizes caution, introspection, and the consequences of past actions.
Listen
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/ika-meji
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ikameji

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Lopelope ejika ni kojewu obo Lopelope kari baba rere bini lomon Adifa fun orunmila Ifa bi fagbemi sile Ifa o bi fagbemi soko Ebo ni won ni baba ose O si gbebo ni be orubo Nje esaje ajodi mon Gbogbo wa lope ojogbe esajape dimon

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ohun pe ire gbogbo fun eleyin ebo ni kose ko si dimon ifa daradara kosi bo orire pelu akuko adire kkan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meji Eyele kan Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Kawo funni Ki emi naa okase fun o Adifafun onika mogun Omo arakika kawo iku ko Ebo ni won ni ko se O sigbebo ni be orubo Nje, kini o bami kawo otako Akinka kosaibani kawo Otako akinka.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ohun pe ire isegun fun eleyin ki orubo ki ole basegun kio si lo fi akuka bori ati tori isegun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran akinka meji Epo Eko Obi Oti
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Okarakara oju kangara Okanjua agba ni n woke radi radi Ejo ni o komo ti eleyin yoyo kari oko Adifa fun kerenulesin Eyi ti yoo gboo gboo Eyi ti yoo too too Eyin tiyo lo egberindinlogun laye Ebo ni won ni ko se O si gbe ebo nibe orubo Nje bi mi kasai legberun odun laye motisin kere naa sin.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyin orubo eni gungun ki eni re ole ba gun ti osi lo fi okete kan bo orire.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Okete aye kan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Kawo funmi kin kase fun o Adifa fun ode Ti n sode re gboje eluju je Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe orubo Nje erekinsin ni bon n wii Eni mogun emon mon dale Ere kisin ni bon wii.

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ohun pere fun eleyin ni okere sun gbon ki omon lo inu meji tori ki ire na ole ba to lowo kio si lobogun pelu eyele merin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele merin Akuko adie kan

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao wa ewe sajeje ewe okika ao fi se eran aki ka je ni epo ni yo awon ohun ti abaje kan ni be ao gun monose dudu eni naa yio maafi we. ISEGUN

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju ewe gbegbe ati ori ejo ao wa jopo eni naa yio fi sin gbere larija yio fi iyoku joko ninu fun ojo meta.

Videos

Watch Ika Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Ika Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ikameji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Íká Ogbè, Íká Òyèkù, Íká Iwòrì, Íká Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ika Meji Odu.