Feed Blog Circles Pages Dashboard
Create Post Create Blog Create Alchemist Create Memorial Create Circle Create Page
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
I

Ika Iwori

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Aliases: Ikawori
Odu Ifa BODE Oracle Sacred Pattern
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness in personal growth.
0 views Updated Jun 19, 2026 epilda.com/odu/ika-iwori
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
Aliases: Ikawori

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

ESE KINI
(1)
Ika fefe lafoye
Iwori fefe lafogba
Adifafun ewiri ti se obinrin Ogun
Igba ti n fomi oju sogbere omo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo nitori omo ki o lobo ewiri agbede pelu akuko adie ati obi pelu oti

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adie meta
Agbebo adie meji
Eyele funfun meji
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ifa ni poki are de o Ojonleke Adifafun orunmila
Baba o fi oro gbogbo se erinrin Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Nje poki are deo
Ojonleke

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o mon mon binu si gbogbo oro ti won ba so fun ki nkan re ole mon da.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meta
Akuko adie meta
Epo
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

(3)
Ikafefe la foye
Iwori fefe la fogba
Adifa fun oniyan hanyan
Ti ntorun bow a saye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi o lobo ori re dada tio ba si ti ji ko mon sure fun ori re larolaro ko mon toro nkan to ba fe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etumeji
Pepeye meji
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

(4)
Ika fefe la foye
Iwori fefe la fogba
Adifafun agidingin
Ti won n ran se ilku pe lorun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ki eleyi orubo nitori iku ko fi eyele merin se irapada emi re nipase alakala ti n la

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele merin
Ko fi igbin bo orisa
Akuko adie meji
Agbebo adie fun

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ewe okirika merindinlogun ewe tete adayeba merindinlogun eyo iyere merindinlogun aolo papo ao fi se eyele ti a ge si merindinlogun je ao tee fun ni odu ifa ikawori ao se adura si ao ko je pata pata

Videos

Watch Ika Iwori teachings on our channel.

Explore Ifa

Ika Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ikawori. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Ika Ogbe, Ika Oyeku, Ika Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ika Iwori Odu.