Àjẹ Àkọlé àwòrán Àwọn àyíká Àwọn ojúewé wọ̀nyí jápọ̀ mọ́ Orisa
Ṣafikun Iṣẹ Fún Ìrántí Ikú Ṣẹ́ Ìyíká Ṣiṣeto Aaye
AD

Àwọn ojúewé wọ̀nyí jápọ̀ mọ́ Odu:

Ìkìlọ̀ nípa àyíká fún gbogbo òpópónà Odu.

Fún Àwọn Tó Ń Gbọ́ Èrò Rẹ
Èmi

Ika Meji

Ika Meji tí wọ́n tún ń pè ní Ikameji
Àwọn orúkọ oyè:Ikameji
Odu Ifa BODE Oracle 2 Èdè Àpẹẹrẹ Mímọ́
Ika Meji nínú Ifa Divination ṣàpẹẹrẹ ìfòyemọ̀, ṣíṣe àfojúsùn ara ẹni àti ohun tó máa ń yọrí sí.
Fetí sí mi
Àwọn ojúewé wọ̀nyí jápọ̀ mọ́: A ṣe àtúnṣe ní April 9, 2026 epilda.com/odu/ika-meji
Ka nínú: Èdè Yorùbá Èdè Spanish èdè gẹ̀ẹ́sì Èdè Português Èdè Faransé
Odu Ifa Àpẹẹrẹ Ìfọkànsìn Mímọ́
Àwọn orúkọ oyè: Ikameji

Àwọn àmì Odu mímọ́ tí wọ́n gbé sára àwo ìsọfúnni tó ń jẹ́ Ópele tàbí Ikin

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Lopelope ejika ni kojewu obo Lopelope kari baba rere bini lomon Adifa funorunmilaIfa bi fagbemi sile Ifa o bi fagbemi soko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ohun pe ire gbogbo fun eleyin ebo ni kose ko si dimon ifa daradara kosi bo orire pelu akuko adire kkan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire mejiEyelekan Epo Eko Obi
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Kawo funni Ki emi naa okase fun o Adifafun onika mogun Omo arakika kawo iku ko

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ohun pe ire isegun fun eleyin ki orubo ki ole basegun kio si lo fi akuka bori ati tori isegun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran akinka meji Epo Eko Obi Oti
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Okarakara oju kangara Okanjua agba ni n woke radi radi Ejo ni o komo ti eleyin yoyo kari oko Adifa fun kerenulesin Eyi ti yoo gboo gboo Eyi ti yoo too too Eyin tiyo lo egberindinlogun laye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyin orubo eni gungun ki eni re ole ba gun ti osi lo fi okete kan bo orire.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Okete aye kan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Kawo funmi kin kase fun o Adifa fun ode Ti n sode re gboje eluju je

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ohun pere fun eleyin ni okere sun gbon ki omon lo inu meji tori ki ire na ole ba to lowo kio si lobogun pelueyelemerin

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyelemerin Akuko adie kan

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao wa ewe sajeje ewe okika ao fi se eran aki ka je ni epo ni yo awon ohun ti abaje kan ni be ao gun monose dudu eni naa yio maafi we. ISEGUN

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju ewe gbegbe ati ori ejo ao wa jopo eni naa yio fi sin gbere larija yio fi iyoku joko ninu fun ojo meta.

Videos

Watch Ika Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Ika Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

This Odu is also known as: Ikameji. Understanding all its names helps in recognizing it across different Ifa lineages and traditions.

Odus that share the same family or pairing include:Ika Ogbe,Ika Oyeku,Ika Iwori,Ika Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa | Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ika Meji Odu.