Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Í

Íká Ósà

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu highlights the importance of adaptability and flexibility in navigating life's challenges.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/ika-osa
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Kasa ni abi kaja ni Adifafun olugbo Ti nlo lee ra ada leru Won ni ko gbebo korubo Igba aisebo Igba aiteru Eyin orifa awo ki biti nse

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi o rubo lori nkan ti of era tabi nkan ti ofe se ki o mon je pe nkan naa ni yio mon gbogun ti. Ifa pe ki eleyi orubo nitori pe agbara re ko ka nkan tin se awon aye si npegan re, ifa pe ipare yi o ka aye.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu meji Akuko adie meji Epo Eko Eyele meta Eye etu meji Oruka ti won nfi sowo meji Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Ika awo etutu Adifafun ada Ti n se awo lo ogba awo Ebo ni won ni kose O si gbebo orubo Ada ogbofa Etutu lada mon Awo rere lo metutu

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi o mon se etutu daada ifa bi oba se nse etutu si ni nkan re o mon yio ri si rere

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu meji Okete Akuko adie meta Epo Eko
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Mo bawo Mo ka wo Adifafun ada Ti ngbogun lo iluigbo Ebo ni won ni kese Osi gbebo nbe orubo Kee pe Kee jina E ba ni laruse ogun Ika ko aturupon dere Adifafun iba Tise Omo odudua Igba ti ntorun bowa sile aye Ebo ni won ni ko se Osi gbebo nbe orubo Nje iba baba iba yeye Iba oluwo iba odugbona Iba oun tawo dase Koro mon sai gba

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi o rubo isegun lori nkan ti o fe se ifa pe ire isegun fun Ifa pe ki eleyi o mon juba fun awon ti won julo ki o si mon se afojudi si enikankan

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Odidi ada kan Akuko adie meji Agbebo adie meji Epo ati eko Akuko adie meta Eyele funfun meji Epo Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Ika sa ika ba Eyinkule nika we Adifafun temi lese Ti nrugba ipin kirin Temi ese ese Ise orimi ran mi Ni mo nje kiri Ika tuwo Ipon tu se Adifafun olongo Ti se elewu iyi Ebo ni won ni ko se Osi gbebo nbe orubo Nje olongo de elewon iyi Kosile ti olongo keewo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa pe ki eleyi o mon sun orire loro mon ki osi mon bo ori re dada ifa ni ori re ni o se gbogbo nkan to base fun Ifa pe ki eleyi o rubo iyi ki o le mon gbayi nibikibi ti obalo ki aye le mon fe tie

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eja aro tutu fun ori re Eye etu meji Akuko adie meji Eyele meji Epo Eko Eyele meji Eyeetu meji Akuko adie meji

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

ISEGUN Ogbe ori akuko ti won fib o esu ori eye etu ti won fi rubo odidi atare kan pelu egbo ope Ifa a o jo papo ao te ni ika osa a o se adura si Abe Olukondo ni won o fi sin gbere na si orikerike ara A o mon fi iyoku fo eko tutu mun. IRE AJE Ewe itebi ewe damonto ao gun papo mon iyere ao fi se alahun kan lepo ni yonje ao te iyere osu ni odu ifa IKA oturupon

Videos

Watch Íká Ósà teachings on our channel.

Explore Ifa

Íká Ósà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Íká Ogbè, Íká Òyèkù, Íká Iwòrì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Íká Ósà Odu.