Í
This Odu represents the balance between wisdom and action in decision-making.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Ifa ni ka ka bara
Kakura nbe
Adifafun iyan
Iyan nraye apinje
Ebo ni won ni ko monse igbatu ebo igbaitu eru
Igbatu ebo igbaitu eru
Eri ifa awo ki biti nse
Ifa de alase ope abise warawara
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi o rubo apesin ki ole ri eni pesin ki osi mon yo ayoju
Ki eleyi o mon yo ayoju lori nkan ti oba nse ki o si gbo ikilo papa laarin awon ti oba wa
Ki eleyi orubo nitori omo ni o ki osi mon se aigboran ki araye o mon ba mon fi tipatipa aba Omo lowo re
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele meta
Eyeetu meji
Akuko adie meta
Epo
Eko
Eran agilinti
Akuko adie meta
Epo
Eko
Agbebo adie meta
Eku
Eja
Epo
Eko
Obe tuntun
Kunmon
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ISEGUN
Ori eye etu meta eku asinrin kan odidi atare meta ewe rekureku topo dada ao jo papo aolokun na afeni odu ifa Aso gbogbo nkan ti abafe ni isegun si ao ro sinu ato kan ao mon fi foko tutu mon larolaro idire ko gbodo kanle mon o
Ewe aje ao lo pelu iyere ao fi se eyele funfun kan lepo niyo ao te iyere osu ni (ika obara)
AJE
Ewe wonjo pupa aolo pelu iyere ao fi se igbin apinnu meji lepo niyo ao te iyere osun ni IKA KANRAN ao se adure si ao keje
Explore Ifa
Íká Óbárà is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Íká Ogbè, Íká Òyèkù, Íká Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Íká Óbárà Odu.
