Í
This Odu signifies the power of patience and strategic planning in achieving success.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Moduro owo mi oto isin
Mobere owo mi oto isin
Awon agba kan agba kan
Won ni ki n dubu yeke
Isin wo simi lenu
Adifafun ejika gogoro
Ti ogbe awo dide
Awon ni o gbe awo dide
Ejika gogoro ni ogbe
Osun de igbo
Awo ni o gbe awo dide
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ni ti osun mon eleyi ni yio saanu re ifa pe ki eleyi o sirubo nitori aare
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko kan
Eyele meji
Epo
Eko
Akuko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Afa obe la fi owo
Nu opo opo ori eni
Ti yo ro fun
Adifafun oti minhinminhin
Igbati nfomi oju sogbere omo
Ebo ni won ni ko mon se
Osi gbebo nbe orubo
Ero opo ero ofa
Eba ni ni jebutu omo
Ese rere egbe awo dide
Adifafun orunmila
Baba nfomi oju sogbere aje suurusu
Ebo ni won ni kose
Osi gbebo nbe orubo
Nje eni to mon awo ni
Ogbe awo dide
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe ki eleyi o rubo ntori omo ki agan tin be legbe eleyi orubo nitori omo
Ifa pe ki eleyi o rubo ko leri alanu ki alaanu ko mon ba Jinna si ifa pe ebo ni koru
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Agbebo adie merin
Akuko adie merin
Obi
Oti
Eku
Eja
Epo
Eko
Eye etu meji
Eyele meji
Akuko adie meji
Epo
Eko
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Moduro owo mi oto isin
Mobere owo mi oto isin
Awon agba won no la
N dubu yeke modubuyeke
Adifafun osun gagaga
Ti se omo okunrin ode
Nje osin moriro
Ko mon dubule
Oro gangan laba osun awo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ki eleyi osebo aare ki o mon ba dubule aare
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adie meta
Pepeye meta
Epo
Eko
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
1ISEGUN
Ewe segun sete ewe ijaoke ao gun papo sususu aolo imin orun aopo papo mon ao fi eeru si ao mon fin ni turare.
Ewe sefunsefun aolopelu iyere ao fi se eyin ororo mefa lepo niyo ao wsa te ifa ika olosun ao se adura si dada ao wa je gbogbo re lori en tuntun.
Explore Ifa
Íká Íròsùn is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Ika Meji, Íká Ogbè, Íká Òyèkù, Íká Iwòrì.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Íká Íròsùn Odu.
