Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Oyeku Meji

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Oyeku Meji signifies profound transformation and renewal. It suggests a powerful change in ones life.
Listen
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/oyeku-meji
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oyesese labo loke Omo araye se bi oju mo lomon Adifafun baba yeku yeku Ti won o mope ni oyeku sapana

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii orubo laiku pe ki emi re ole gun ebo ni kose dada.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Oruko kan Epo Eko Obi Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Opa gbogbo ni siwaju agbon nini Ese mejeji ni jija de ona gborogan gborogan Ati pe obi enu bobo aso kitipa abita wele Adifa fun enlojo aso Lojo ti won tode orun bo wale aye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki awon omo iya meta ki won o rub o emi won ki emi won ba le gn ti won ofi aso dudu aso funfun ati aso pupa kobo ru

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aso dudu Aso pupa Aso funfun Eran ewure kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Atefa bere arobiunda Apaju bere airobiunko Sese ega eye ega sese Adifafun laba nile o Imo egba ni ile alake Nigbati oju sogbere ire gbogbo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa niki eleyin orubo kole badaja pe oju aje nip on eleyin ebo ni ko se ba laje loun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku Eja Abodire Ewure Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Won dafa sekeseke nile olufon Moya mowo ranwon Mo lugbbin leyin kule orisa ojiyan Moya mo wo ranwo aroni miini ke, Semi abii arara mi ki seun ati loku Abuke ile irami mi mi kese ni Adi loku gbonigboni sale sale Adifa fun oyela ti n tode orun bowaye

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyin rubo ki ole bala ape oju aye nipon eleyin ki won osi se ifa be si kole ba lowo lowo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Pepeye kan Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

A o toju ina elegede ati ose dudu ao wa gun po ao ma fi we laro laro ISEGUN

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao toju ewe ayure pelu ewe apada ao wa jo po mo odidi atare kan a o wa fi sin gbere mokanlelogun si ori

Videos

Watch Oyeku Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Oyeku Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Ogbe, Oyeku Iwori, Oyeku Odi, Oyeku Irosun.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oyeku Meji Odu.