I
This Odu highlights the importance of wisdom and insight.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Jege jege teri akere ngbe
Iye niko se tu lokun
Adifafun orunmila
Eyi to ti taja sile
Ti gbogbo omo re o mo gbawo kiri
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni ki eleyi orubo ki ise re moba di ise onise korubo ki eni eni mo ba fi se faje ko lo ree bo ifa ki awon omo re ki won o mo ba se damu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Abodie ewure
Obi
Opolopon eyele
Opolpolo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Irosun funfun jingin
Adifafun olowo o jeran finfin alakedu
Igba ti n sogbogbo arun
Tin n nara kaka alailedide
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa nipe alaisan wa larin eewo kan nbe nidile won kije eleyi nje ewo, ewo yi ewo na loda sile ko mo je ewo yi mo
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Oruko
Akukodie
Opolopo owo
Gbogbo nkan inu eran yi pese fun awon to laye
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Igi nla sidi omunre
Ato ro kin torokin
Adifafun orunmila
Baba loun o so a fin olufe di dudu
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pere fun eni to da ifayi korubo if ape awon mefa kan ni won o la eleyi ifa ni ise ti won ngbe bow a fun o le gan sugbon to ba rubo yo se ase yori kosi mun eun lele
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eyele
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
Opolopo agbigba kan odidi atare kan ao fi eyin opolo yi le agbada ao fi odidi atare kan le laya ao wa ko ewe iya lode oyo
pomo arawon ao ni siwo titi yo fijo tan tio ba tan ao lo ao ma fi oti lo ni ekan naa
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
Ewe areyin kosun ewe aje obale aojo po mo odidi atare kan o ma fi fo eko tutu mun laro.
Explore Ifa
Irosun Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irosun Ofun Odu.
