I
This Odu signifies the importance of vigilance and awareness.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
Pasan wara
Adifafun won nirosun omosa
Igba ti fomi oju sogbere ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa so pe eni to dafa yii pe eegun kan wa nidile won ti won ti pati, pe ki o lo ree gbe eegun yii jade, ki won le baa ni aseyori, ki won o fi opolopo akara ati olele pelu eko bo eegun na
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Opolopo pasan
Olele
Akara
Eko
Oruko
Akuko adie
Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Sokoto makin
Sokoto makin
Efin logori eja lokeriri kebekebe
Adifafun atagin ningin
Ti n somokunrin aye
Igba ti n torun bowaye
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni eleyii fe dawoo lenka, ko rubo kin nkan naa ko le baa ja sayo, to ba je pe eleyii fe lo sibi kan ni, ko rubo koto le kinrin ajo naa ko lo so eso rere ki o bo ifa ko to lo.
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eku
Eja
Ewure
Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Irosun sara gaga kanle
Oba tojupo po wol ile
Adifafun gbedako
Tii se aremo ogun
Igba ti raye lainniku
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pe ire fun eni to dafa yii, ifa ni oun ri ire aiku fun, ifa ni ko rubo fun omo re kan nitori iku, ko si boo gun
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire
Opolopo owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Olosunsa aoro olosun
O sa ao ro tepolosoro leje o soro
Adifafun otupata
Tii se aya agboniregun
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa pe oun pere fun eni toda ifa yii, ifa ni ki iya eleyii ko mota epo pupa to ba je pe obinrin komo ta epo ko si mun nire kofi pa ese fun awon iyami
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire
Eyele
Opolopo owo
Explore Ifa
Irosun Osa is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Irosun Meji, Irosun Ogbe, Irosun Oyeku, Irosun Iwori.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Irosun Osa Odu.
