O
This Odu highlights the need for introspection and self-awareness in personal growth.
Odu Ifa Sacred Divination Pattern
The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray
1
Ese Kinni
Ese Kinni
Ese — Yoruba Verse
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa pe oun pe ire omo fun elelyi
EBO ni kose kio silo bo ifa pelu
eran ewure odidi kan
Ifa sope oun pe ire gbogbo fun eleyi pe ibikan ni eleyi loyi korubo kole bagbayi bo ni be kio lobo ifa pelu eran ewure
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eran ewure odidi kan
Epo
Eko
Obi
Eran ewure kan
Epo
Eko
Obi
2
Ese Keji
Ese Keji
Ese — Yoruba Verse
Ogede dundun awo iwere
Adifafun erinlegbejo ilawo
Nijo ti won kowo rode oyo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire isegun pe oun
pe ire aiku fun eleyi ki eleyi
osi mon daja kio bo orisala
pelu igbin merin kio fi akuko adire bo esu
ifa ni oun pe ire aje fun elelyi
pe oju aje lopon elleyi kio lobo aje
pelu eye etu ekuru ogede eyin
oyin obi
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Akuko adire kan
Igbin merin
Epo
Eko
Obi
Eye etu
Oyin
Eyin
Ekuru
Obi oti
Epe
Eko
3
Ese Keta
Ese Keta
Ese — Yoruba Verse
Lata npopo awo egbe
Adifafun won ni monlasese agere
Nijo ti won momi oju sogbere ire gbogbo
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
ifa ni oun pe ire gbogbo fun
eleyi ki eleyi olobo aje pelu
eye etu kio sifi eku eja agbebo adire kan bo ifa
ifa sope oun pe ire aiku fun eleyi
ki elelyi olobo orisala pelu opoloo
igbin kio sifi eran oruko kan tu ebo fun esu
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
Eye etu kan
Abo adire kan
Eja
Obi
Epo
Eko
eran oruko kan
opolopo igbin
epo
eko
obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin
Ese — Yoruba Verse
Ponlawi Ponlawin
Adifafun Ipon ni jo tigbogun lo ilobe
✦
Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)
Ifa ni oun pe ire isegun fun elelyi ebo ni ki elelyi ose kio si fin oruko kan ru ebo
ifa ni oun ope ire isegun fun elelyi
ki elelyi olo fi ewure meji rubo
kiwon ofi okan bo ifa ki won
ofi okan pe se fun awon agbalagba EBO
Eran ewure meji
Epo pupa pupo
Eko
Obi
Oti
Ebo — Sacrifice (Yoruba)
eran oruko odidi kan
epo
eko
obi
Awure — Alchemist Formula
Yoruba
ele wa ao wa gun po mon ose dundun ao wad a lofinda si toba lorudaradara ao wa ko sinu ike funfun ao wa mon fi we larolaro
AWURE
ao toju ewe gbodogin pelu iyere
ao wa lopo ao wa fi se igbin
mefa lepo ni yo ao wa ja igbin
yi ni idi ao ko idire dede yi sibika pelu gbogbo awon oun ti abale se nui be sinu agbada ao wa tunmu ewe gbodogin yi si ao wa jo po mon odidi atare kana o wa je obe yi ao mon fi oti lo ebure
Isegun / Akose — Victory Formula
Yoruba
ISEGUN
Ao toju igi legunoko ao toju
ogede dundun pelu atare kana o wa jo papo toba jo tan ao wa fi si gbere ogoji ati eyo kan si arin ori wa fi iyoku fo eko mu
iya yin ao toju ewe apada ati ewe segun sete ao wa gun mon ose dundun ao wa mon fi we laarolaro
Explore Ifa
Oturupon Iwori is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).
Odus that share the same family or pairing include: Oturupon Meji, Oturupon Ogbe, Oturupon Oyeku, Oturupon Odi.
Reflections & Testimonies
Be the first to share a reflection on Oturupon Iwori Odu.
