Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Oyeku Ofun

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents wisdom and the ability to see beyond the surface to understand deeper truths.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/oyeku-ofun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Itakun peele awo eba ona Adifafun aake oun iroko Nijo ti won jo n sota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eleyii n ba eni kan sota, pe eni naa juulo sugbon ebo ni ko ru, ko le baa segun eni naa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aake kan Akuko adie kan Epo Eko Agbado Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Orooro adi Adifafun adie okooko Ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo fobinrin re, ki awon ota o mo baa pa a molowo, ki iyawo re naa o si ma ki oloku tabi alaare fun ojo merindinlogun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meji Igbin meji Obi meje Epo pupa Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Igijegede sogbade Adifafun mansinwo Tii somo itobi laafi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni keleyii o rubo lenu ise re pe yoo la ko si ma sinwo lenu ojo meta yoo nitori aje.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo obi Eku emon meji Epo Eko Agbado Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Igijegede sogbade Adifafun Aganronke Ti n sawo relu okere

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ibi kan ni eleyii nlo pe korubo yoo sir ire bo nibe.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Epo Eko Agbado Owo

Videos

Watch Oyeku Ofun teachings on our channel.

Explore Ifa

Oyeku Ofun is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Meji, Oyeku Ogbe, Oyeku Iwori, Oyeku Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oyeku Ofun Odu.