Feed Blog Circles Pages Dashboard
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
AD

Support Family Memorials

Dedicated landscape slot for memorial routes.

Create Memorial
Ò

Òyèkù Òfún

Odu Ifa — Sacred Verse of the Oracle
Odu Ifa Yoruba Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents wisdom and the ability to see beyond the surface to understand deeper truths.
0 views Updated Mar 28, 2026 bode.ng/odu/oyeku-ofun
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Itakun peele awo eba ona Adifafun aake oun iroko Nijo ti won jo n sota Ebo ni won ni ki won o se Aake nikan ni n be leyin ti n tubo Ero ipo Ero ofa E bani larusegun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni eleyii n ba eni kan sota, pe eni naa juulo sugbon ebo ni ko ru, ko le baa segun eni naa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Aake kan Akuko adie kan Epo Eko Agbado Opolopo owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Orooro adi Adifafun adie okooko Ti n be laarin ota Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Nje, ifa o to gege kooba mi segun ota mi

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo fobinrin re, ki awon ota o mo baa pa a molowo, ki iyawo re naa o si ma ki oloku tabi alaare fun ojo merindinlogun

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eyele meji Igbin meji Obi meje Epo pupa Eko Agbado Owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Igijegede sogbade Adifafun mansinwo Tii somo itobi laafi Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E bani bola peregede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni keleyii o rubo lenu ise re pe yoo la ko si ma sinwo lenu ojo meta yoo nitori aje.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Opolopo obi Eku emon meji Epo Eko Agbado Owo
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Igijegede sogbade Adifafun Aganronke Ti n sawo relu okere Ebo ni won ni ko se O si gbebo nibe o rubo Ero ipo Ero ofa E wa bani bola peregede

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ibi kan ni eleyii nlo pe korubo yoo sir ire bo nibe.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire kan Epo Eko Agbado Owo

Videos

Watch Òyèkù Òfún teachings on our channel.

Explore Ifa

Òyèkù Òfún is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that form the foundation of the Yoruba oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyekú Méjì, Òyèkù Ogbè, Òyèkù Iwòrì, Òyèkù Òdì.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Òyèkù Òfún Odu.