Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Ofun Meji

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
Ofun Meji in Ifa Divination symbolizes clarity, wisdom, and the power of divine enlightenment.
Listen
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/ofun-meji
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Onaa gbororo lejo fi gun agbon Adifafun orangun Nijo ti won n pe lalade orun

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa nipe ohun pe ire laiku fi eleyi orubo emi re ko si fi ejo kun ebo run ko si mu oti ni ojo tio ba da ifa yii daradara

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko Adire meji Ori Ejo Oti Obi Epo Eko
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Eruku tororo Eruku tarara Adifa fun eji orangun Nijo ti sawo lo ile ilesan

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire gbogbo fun eleyi pe ibikan ni eleyi loyin koru bo kole ba ri re mu bo ni be kio si lobo ifa pelu eran ewure.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eran ewure kan Epo Eko Obi
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Adeyeri Lawo alajiki Ade tuntun Lawo aji feran rere lo Adifa fun orunmila Ni jo ti lole gbaye tuntun ni yawo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire aya fun eleyi pe oju aya ni pon eleyi ebo ni ko se ko le ba di alaya kio si fi eku eja abodie bo ifa.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eku kan Eja kan Abodire kan Epo Eko Obi
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Bagbon osoro Atidi bole Ida soro teku bako Bi alamu osoro Atidi bo eba ogiri Adifa fun korowo ti nbe laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ohun pe ire isegun fun eleyi ki eleyin orubo isegun tio si lo bo ifa pelu eran elede odidi kan ti won ba fe pa elede yii won yio tori re boo mi ki won oto pa

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Odidi elede kan Epo Eko Obi

Awure — Alchemist Formula

Yoruba

Ao mu eweeyin olobe die pelu iyere ao fi se adire meje tobaje obinrin mesan toba je okunrin kia toje obe ni odi igba ti owo bapa tese pa la le ni ao toje obe naa ao wa so gbogbo obe naa. ISEGUN

Isegun / Akose — Victory Formula

Yoruba

Ao mu eran elede ao toju agbon ile kana o toju ako alangba kana o wa jo gbo gbore papo mon ewe apada ao wa po mon ose dudu eni naa yio mon fi we laro laro.

Videos

Watch Ofun Meji teachings on our channel.

Explore Ifa

Ofun Meji is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Ofun Ogbe, Ofun Oyeku, Ofun Iwori, Ofun Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Ofun Meji Odu.