Feed Blog Circles Pages Orisa
Add Post Add Memorial Create Circle Create Page
AD

Sponsor Odu Knowledge Pages

Landscape ad for all Odu routes.

Reach Audience
O

Oyeku Osa

Odu Ifa — Sacred Verse and Divination Wisdom
Odu Ifa BODE Oracle 2 Languages Sacred Pattern
This Odu represents the need for caution and careful planning to avoid unforeseen dangers.
0 views Updated Apr 9, 2026 epilda.com/odu/oyeku-osa
Read in: Yoruba Español English Português Français
Odu Ifa Sacred Divination Pattern

The sacred Odu marks as cast on the Opele or Ikin divination tray

1
Ese Kinni
Ese Kinni

Ese — Yoruba Verse

Oyeku teku asa O yan kete kete Adifafun popondo Eni ti o gbori ote re dade

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ki eleyii o rubo, pe aarin ota ni eleyii wa, sugbon aarin ota naa ni yoo ti la.

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Akuko adire meji Eyele meji Abo adie meji Epo Eko Agbado Owo
2
Ese Keji
Ese Keji

Ese — Yoruba Verse

Oyeku teku asa oyan kete kete Adifafun abe sekete ti n be laarin ota

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni awon ota eleyii ju eleyii lo paa paa won ni agbara juu lo, pe ki eleyii o rubo gbogbo won ni n won o wa maa foribale bale fun un

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Abe fele meta Akuko adire meta Epo Eko Agbado Opolopo owo
3
Ese Keta
Ese Keta

Ese — Yoruba Verse

Oyeku sale babe Eruku so gbagba nin poro oko Adifafun Erigi alo Tii segbon ope agbe Igba ti n fomi oju sogbere aje suru suru

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ire aje n bo feleyii lati okere, oore naa sipo gidi gidi, pe ki eleyii o rubo koore naa o le too lowo

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Eye etu meji Owo Epo Eko Agbado
4
Ese Kerin
Ese Kerin

Ese — Yoruba Verse

Eminrin gesin bee ni koni kese Amukuru gesin bee ni ko si bata Ire toni kese toni bata beeni o rese gori esin Adifafun Oyeku it n rele osa lee sawo

Ase — Ifa Spiritual Message (Yoruba)

Ifa ni ibi kan ni eleyii fee lo yii, pe korubo pe yoo ri ire aje mubo nibe

Ebo — Sacrifice (Yoruba)

Iyan ati obe egusi pelu eja Oti Obi Abo adie meji Epo Eko Agbado at owo

Videos

Watch Oyeku Osa teachings on our channel.

Explore Ifa

Oyeku Osa is one of the 256 sacred Odu Ifa — the corpus of divination verses that forms the foundation of the BODE Oracle system. Each Odu contains multiple Ese (verses) alongside their Ase (spiritual power), Ebo (sacrifice), and Akose (alchemical remedies).

Odus that share the same family or pairing include: Oyeku Meji, Oyeku Ogbe, Oyeku Iwori, Oyeku Odi.

← Browse all 256 Odu Ifa  |  Seek Divination

Reflections & Testimonies

0 reflections shared

Be the first to share a reflection on Oyeku Osa Odu.